Facebook

Facebook jẹ́ ìkànnì abánidọ́rẹ̀ẹ́ lórí afẹ́fẹ́ ẹ̀rọ ayélujára.

Ó jẹ́ ìkànnì tí lè ní àǹfààní sí láti orí foonu alagbeka, ẹ̀rọ kọ̀m̀puta tábìlì àti èro komputa agbelowo tí ó ní àmúmọ̀ láti já lú ayé lórí afẹ́fẹ́. Ilé Iṣẹ́ tí ó ń ṣe kòkárí rẹ̀ gúnwà sí Menlo Park, California, lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ọ̀gbẹ́ni Mark Zuckerberg ní ó ṣẹ̀dá rẹ̀ lọ́dún 2004. . Alefi Facebook fòrò ránsé si olùmúlò Facebook miran, a sì tún le fi Facebook fi foto àti fidio ránsé sawon òré wa.

Facebook, Inc.
TypePublic
Area servedWorldwide
Key people
  • Mark Zuckerberg (Chairman, CEO, Controlling Shareholder)
  • Sheryl Sandberg (COO)
  • David Wehner (CFO)
  • Mike Schroepfer (CTO)
Industry
  • Social media
  • Advertising
Products
Revenue US$55.838 billion
Operating income US$24.913 billion
Net income US$22.111 billion
Total assets US$97.334 billion
Total equity US$84.127 billion
Employees43,030
References:
Facebook
Àwòrán ìdánimọ̀ Facebook

Ka eléyí náà

Whatsapp

Àwọn Ìtọ́kasí


Tags:

CaliforniaFoonu alagbekaMark Zuckerberg

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Odunlade AdekolaBarack ObamaFilipínìÀsìkòH.264/MPEG-4 AVCSantos AcostaYemojaChinedu Ikedieze17 March.jpAdekunle GoldỌdún EgúngúnOgun Àgbáyé KìíníNancy ChartonÀrún èrànkòrónà ọdún 2019ZuluFrançois FillonWeb browserTòmátòNàìjíríàWikimediaWikipẹ́díà l'édè YorùbáISO 31-10Christopher ColumbusOrílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ ṢáínàOsita IhemeÀdìjọ ìtannáJay-Jay Okocha.cmISO 860122 MarchRichard NixonSáúdí ArábíàPrussiaÌmọ́lẹ̀SQLWerner FaymannNamibia1972 Yi XingÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020Mao Zedong3254 BusRené DescartesErin-Ijesha WaterfallsWọlé SóyinkáNigerian People's Party25 JulyÌnáwó.tcEugenio Montale.sbOperating SystemCETEP City UniversityOṣù KejeEarthTibetVieno Johannes SukselainenDolby DigitalAgbonIngrid AndersenÀṢÀ ÌKÍNI NÍ ÀWÙJỌ YORÙBÁFáwẹ̀lì YorùbáStuttgartVladimir PutinPrologÀṣà18946 Massar🡆 More