Àrún Èrànkòrónà Ọdún 2019

Àrùn èrànkòrónà ọdún 2019 (tàbí ní èdè gẹ̀ẹ́sì bíi Coronavirus disease 2019, COVID-19) jẹ́ àrún àkóràn kan tí èràn àrọ́lù àìsàn ìmín olóró gbígboró, èràn kòrónà irú 2 (SARS-CoV-2) ń mú wá.

Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa àrún náà. Fún kòkòrò èràn tó ún fàá, ẹ wo: SARS-CoV-2.

Àrùn náà kọ́kọ́ jẹ́ dídámọ̀ ní December 2019 ní Wuhan, ní China, tó sì ti ràn ká gbogbo àgbáyé láti ìgbà náà pẹ̀lú ajakale-arun kaakiriaye erankorona odun 2019-2020. Nínú àwọn ami-aisan rẹ̀ tó wọ́pọ̀ ni iba, ikọ́, àti àìlèmín balẹ̀. Àwọn àmì àìsàn míràn tún lè jẹ́ irora, híha kelebe, igbe olomi, ikanra ona-ofun, ainlegbo oorun, ati irora ikun. Botileje pe opo alaisan arun yi ni ami-aisan to loworo, awon miran le ni eran edo ati ikuna patapata opolopo ifun-ara. Titi di ojo 3 April 2020, iye awon alaisan COVID-19 ti a mo lagbaye je 1,040,000, iye awon alaisi je 55,100 deaths.Iye awon ti ara won ti ya je 221,000.

Àrún èrànkòrónà ọdún 2019 (COVID-19)
Symptoms of COVID-19Àrún èrànkòrónà ọdún 2019 (COVID-19)
Symptoms of COVID-19Àrún èrànkòrónà ọdún 2019 (COVID-19)
Symptoms of COVID-19
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta

Àwọn Ìtọ́kasí

Drink green tea, take Vitamin C, turmeric, ginger and elderberry, eat oranges, fruits and vegetables. Use hand sanitizer and wear mask on airplane.

Tags:

2019–20 coronavirus pandemicChinaFeverSARS-CoV-2

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Fyodor DostoyevskyJulian Apostat1 OctoberCondoleezza RiceParáG.722.1Operating SystemKàlẹ́ndà GregoryNigerian People's PartyUnasPúẹ́rtò RíkòElihu RootBaruch SpinozaUlf von EulerÌjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020InstagramYukréìnAtọ́ka Ìdàgbàsókè ÈnìyànCôte d'IvoireSalvatore QuasimodoWasiu Alabi Pasuma3 NovemberLouis 13k ilẹ̀ FránsìOṣù KẹtaWale OgunyemiÌwé àwọn Onídàjọ́EyínÌgèNọ́mbà àkọ́kọ́Mary Akor22 MayFIFABD Mimọ23 AprilPsamtik 1k2010Àṣà Ìsọmọlórúkọ Nílẹ̀ Yorùbá24 JuneISO 5964Ayo AdesanyaÌhìnrere LúkùRichard Mofe DamijoHypertext Transfer Protocol2437 Amnestia.gyPotsdamAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ BindawaPolinésíàIgbesi aye mi ninu igbo ti Awọn ẹmi (aramada)KhabaChemical elementCoat of arms of South KoreaVladimir PutinRita DominicMillicent AgboegbulemOrílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú ilẹ̀ KóngòMwambutsa 4k Bangiriceng ilẹ̀ BùrúndìÀwọn sáyẹ́nsì àwùjọÀrún èrànkòrónà ọdún 2019EwìDNA🡆 More