Millicent 'Milli' Agboegbulem (tí wọ́n bí ní 18 June 1983) jẹ́ afẹ̀ṣẹ́jà ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó ń gbé ní ìlú Australia.
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ onídẹ ní 2018 Commonwealth Games.
Statistics | |
---|---|
Rated at | Middleweight |
Nationality | Nigerian |
Birth date | 18 Oṣù Kẹfà 1983 |
Birth place | Nigeria |
Millicent kópa nínú ìdíje àwọn afẹ̀ṣẹ́jà ti Commonwealth ti ọdún 2018. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ onídẹ ní ìdíje náà.
Ní oṣù kẹta ọdún 2023, Agboegbulem díje dupò oyè Australian Super Welterweight Champion pẹ̀lú Desley Robinson, ó sì borí. Ní oṣù keje ọdún 2023, Agboegbulem jìjàkadì pẹ̀lú Tayla Harris láti di oyè náà mú. Harris tóbi, kò sì sí ẹni tó borí nínú ìjà pẹ̀lú rẹ̀ rí, àmọ́ Agboegbulem jáwé olúborí nínú ìdíje náà.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Millicent Agboegbulem, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.