Bitcoin

Àdàkọ:Special characters

Bitcoin
Wiki YorùbáPrevailing bitcoin logo
Prevailing bitcoin logo
Denominations
Pluralbitcoins
Symbol
Ticker symbolBTC, XBT
Precision10−8
Subunits
11000millibitcoin
1100000000satoshi
Development
Original author(s)Satoshi Nakamoto
White paper"Bitcoin: A Peer-to-Peer Electronic Cash System"
Implementation(s)Bitcoin Core
Initial release0.1.0 / 9 Oṣù Kínní 2009; ọdún 15 sẹ́yìn (2009-01-09)
Latest release0.18.0 / 2 Oṣù Kàrún 2019; ọdún 4 sẹ́yìn (2019-05-02)
Development statusActive
Websitebitcoin.org
Ledger
Ledger start3 Oṣù Kínní 2009; ọdún 15 sẹ́yìn (2009-01-03)
Timestamping schemeProof-of-work (partial hash inversion)
Hash functionSHA-256
Issuance scheduleDecentralized (block reward)
Initially ₿50 per block, halved every 210,000 blocks
Block reward₿12.5
Block time10 minutes
Block explorerbitaps.com/
Circulating supply₿17,754,100 (títí di 11 Oṣù Kẹfà 2019 (2019 -06-11))
Supply limit₿21,000,000

Bitcoin (, Bítkọìn ní gbólóhùn Yorùbá) jẹ́ owóníná onísíṣeàmìkíkọpamọ irú owó kíkà orí kọ̀mpútà kan. O jẹ́ owóníná orí kọ̀mpútà aláìníolùgba-àrin tí kò ní bánkì agba-àrin rárá tí ẹníkan le fún ẹlòmíràn lórí ẹ̀rọ kọ̀mpútà álásopọ̀ ọ̀rẹ́sọ́rẹ̀ẹ́ láì sí ẹnìkankan ní àrin wọn.

Àwọn kọ̀mpútà alásopọ̀ nodes ló ún ṣe ìjẹ́ẹ̀rí àwọn ìdúnàádúrà tó únṣẹlẹ̀ pẹ̀lú ìṣeàmìkíkọpamọ́ tí wọ́n jẹ́ kíkọ sínú ìwé-àkọọ́lẹ̀ pípínkiri tó hàn sí gbogbo ènìyàn tí à ún pè ní blockchain. Bitcoin jẹ́ dídá sílẹ̀ látọwọ́ ẹnìkan tàbí ọ̀pọ̀ àwọn ẹníkan tí orúkọ wọn únjẹ́ Satoshi Nakamoto tó sì jẹ́ fífi s'óde gẹ́gẹ́ bíi ìlànà ìṣiṣé kọ̀mpútà atúdìísílẹ̀ ní ọdún 2009. Àwọn bitcoin únjẹ́ dídá gẹ́gẹ́ bi ẹ̀san fún ìgbéṣẹ̀ kọ̀mpútà tí à ùn pè ní mining. Wọ́n ṣe é fi ṣe pasípàrọ̀ fún àwọn owóníná míràn, èso-iṣé àti ìránṣe-iṣẹ́.



Itokasi

Àdàkọ:Bitcoin Àdàkọ:Cryptocurrencies

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Hugo ChávezLinuxIndonésíàÀdírẹ́ẹ̀sì IPÌbálòpọ̀Boris Yeltsin67085 OppenheimerMao ZedongOṣù KẹtaÒrò àyálò YorùbáGbólóhùn YorùbáAli Abdullah SalehAtlantaOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́Orílẹ̀ÀkàyéEast Caribbean dollarLọndọnuInternetSean ConneryOranmiyanChinua AchebeSíńtáàsì YorùbáEarthOwo siseÈdè YorùbáPierre NkurunzizaỌjọ́ RúÌtànISBNVictor Thompson (olórin)ÌwéKàlẹ́ndà GregoryMathimátíkìÀgbérò PythagorasỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀23 JuneẸ̀bùn Nobel nínú Lítíréṣọ̀YDiamond JacksonBeirutRio de JaneiroItan Ijapa ati AjaFilipínìIsaiah WashingtonIyàrá ÌdánáIkúAlẹksándrọ̀s OlókìkíOdunlade AdekolaAustríàÌgbéyàwóOlógbòOṣù Kínní 15Allwell Adémọ́láPópù Sabinian28 June🡆 More