Hypertext tàbí Ikokoja jẹ ikọ̀ lórí kọ̀mpútà tàbí ohun ẹ̀rọ afinásisẹ́ míràn, pẹ̀lú àwọn ìtọ́kasí (ijapokoja) sí àwọn ikọ̀ míràn tí olùkàwé lè lò kíákíá, bóyá pẹ̀lú Click èkúté (mouse) tàbí títẹ̀ bọ́tínì lórí pátákó bọ́tínì.
Lẹ́yìn pé òun fihàn ikọ̀, hypertext tún lè ní tábìlì, àwòrán àti àwọn ohùn ìfilọ́lẹ̀ míràn. Hypertext ní àjọtúmọ̀ lábẹ́ tó ń ṣe ìtumọ̀ ọ̀pọ̀ World Wide Web, tó mú kó jẹ́ kó rọrùn láti lo àti láti pín ìfitónilétí lórí Internet.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Hypertext, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.