Wiki Yorùbá

Adeniran Ogunsanya QC, SAN (31 January 1918 – 22 November 1996) jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó sì tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú Ibadan Peoples Party (IPP).

Ojúewé Àkọ́kọ́
Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Kọmíṣọ́nà fún ètò ìdájọ́ ati ètò ẹ̀kọ́ fún Ìpínlẹ̀ Èkó ní àsìkò ìṣèjọba alágbádá ẹlẹ́kejì. Òun náà tún ni alága pátá pátá fún ẹgbẹ́ òṣèlú Nigerian People's Party nígbà ayé rẹ̀. Wọ́n bí Adéníran ní ọjọ́ Kọkànlélógún oṣù Kíní ọdún 1918 ní agbègbè ÌkòròdúÌpínlẹ̀ Èkó sí agboolé ọmọ Ọba Sùbérù Ògúnsànyà Ògúntádé tí ó jẹ́ Ọdọ̀fin ti ìlú Ìkòròdú nígbà náà. Adéníran lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Hope Waddell Training Institute ní ìlú Calabar nígbà tí ó ń gbé pẹ̀lú àbúrò bàbá rẹ̀ tí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba ní ìlú Calaba. Ìjọba fi ẹ̀bùn ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ dá Adéníra lọ̀lá láti kàwé síwájú si ní ilé-ẹ̀kọ́ King's College tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó látàrí bí ó ṣe peregedé jùlọ pẹ̀lú máàkì tí ó ga jùlọ nínú ìdánwò àṣekágbá ti Standard VI (6) ní ọdún 1937. Ó tẹ̀ siwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti University of Manchester àti Gray's Inn tí ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin.

(ìtẹ̀síwájú...)

Ojúewé Àkọ́kọ́
David Blackwell
David Blackwell

Ọjọ́ 24 Oṣù Kẹrin:

Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...

  • 1919 – David Blackwell (foto), onimo mathimatiki omo Afrika Amerika (al. 2010)
  • 1942 – Barbra Streisand, American singer and actor
  • 1954 – Mumia Abu-Jamal, American Civil Rights activist

Àwọn aláìsí lóòní...

  • 1993 – Oliver Tambo, South African politician (b. 1917)
  • 1993 – Tran Duc Thao, Vietnamese philosopher (b. 1917)
  • 2001Leon Sullivan, African-American civil rights leader and pastor (b. 1922)
Ọjọ́ míràn: 2223242526 | ìyókù...


Ojúewé Àkọ́kọ́
  • ...pé klorínì onífluorínìmẹ́ta le jó yèèpẹ̀ níná?
  • ...pe 3% nikan omi lori Aye lo je tutu?
Ojúewé Àkọ́kọ́
Ojúewé Àkọ́kọ́

Ojúewé Àkọ́kọ́ Ẹ tún wo ÌròyìnWiki ní èdè Gẹ̀ẹ́sì

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Òkun MẹditéránìJẹ́mánìNairobiTheodor Adorno13 DecemberC++Ọ́ksíjìnMaghrebÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 1936RómùDubaiFunke AkindeleStuttgartJẹ́ọ́gráfìPierre Nkurunziza6 MarchKonrad LorenzFọ́tòyíyàIrakPornhubOsama bin LadenFelix OhiwereiNàìjíríàOrin WéréÈdè FaranséDar es SalaamÌgbà Ẹlẹ́funMàríà (ìyá Jésù)GoogleDora Francisca Edu-BuandohLev LandauX15 AprilCornus canadensisSáúdí ArábíàIlẹ̀ọba Aṣọ̀kan Brítánì Olókìkí àti Írẹ́lándìISO 31-1Napoleon 3kMedgar EversOrin hip hopAbubakar AuduElisabeti KejìÌkéde Akáríayé fún àwọn Ẹ̀tọ́ ỌmọnìyànDonald A. GlaserÌṣúpọ̀ olùgbéEpoÀàlàNeanderthalTóyìn AbrahamÀkúrẹ́9 FebruaryÒrùnDelamarentulusÌgbà Òṣèlú Kẹta FránsìItan Ijapa ati Aja202321 MayÌbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kánÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáLinda IkejiGbólóhùn YorùbáÒgbójú Ọdẹ nínú Igbó Irúnmọlẹ̀NamibiaLas VegasEthiopiaJoseph ConradKẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ abilà🡆 More