Ojúewé Àkọ́kọ́

Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Adeniran Ogunsanya QC, SAN (31 January 1918 – 22 November 1996) jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó sì tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú Ibadan Peoples Party (IPP). Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Kọmíṣọ́nà fún ètò ìdájọ́ ati ètò ẹ̀kọ́ fún Ìpínlẹ̀ Èkó ní àsìkò ìṣèjọba alágbádá ẹlẹ́kejì. Òun náà tún ni alága pátá pátá fún ẹgbẹ́ òṣèlú Nigerian People's Party nígbà ayé rẹ̀.Wọ́n bí Adéníran ní ọjọ́ Kọkànlélógún oṣù Kíní ọdún 1918 ní agbègbè ÌkòròdúÌpínlẹ̀ Èkó sí agboolé ọmọ Ọba Sùbérù Ògúnsànyà Ògúntádé tí ó jẹ́ Ọdọ̀fin ti ìlú Ìkòròdú nígbà náà. Adéníran lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Hope Waddell Training Institute ní ìlú Calabar nígbà tí ó ń gbé pẹ̀lú àbúrò bàbá rẹ̀ tí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba ní ìlú Calaba. Ìjọba fi ẹ̀bùn ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ dá Adéníra lọ̀lá láti kàwé síwájú si ní ilé-ẹ̀kọ́ King's College tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó látàrí bí ó ṣe peregedé jùlọ pẹ̀lú máàkì tí ó ga jùlọ nínú ìdánwò àṣekágbá ti Standard VI (6) ní ọdún 1937. Ó tẹ̀ siwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti University of Manchester àti Gray's Inn tí ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin.

(ìtẹ̀síwájú...)

Máápù Siẹrra Léònè

Ọjọ́ 18 Oṣù Kínní:

Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...

Àwọn aláìsí lóòní...

Ọjọ́ míràn: 19 · 20 · 21 · 22 · 23 | ìyókù...


Ayé

Damages after 2020 Beirut explosions 1.jpg

Ẹ tún wo ÌròyìnWiki ní èdè Gẹ̀ẹ́sì
Èdè
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Àṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáÌran YorùbáÈdè YorùbáWikipedia:Abẹ́ igiÀwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáPàtàkì:SearchWikipedia:Èbúté ÀwùjọIlẹ̀ YorùbáÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Àṣà YorùbáWikipedia:Nípa WikipediaÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíYemenÀrokòEre idarayaISO 8601KinshasaÌṣọ̀kan ÁfríkàÀsà ilà kíkọ ní ilé YorùbáÌbàdànOrílẹ̀-èdè YorùbáTurkeyDọ́là Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàÌrànwọ́:Báwo lẹṣe le ṣe àtúnṣe ojúewéJack BlackỌ̀rúnmìlàẸ̀ka:Àwọn Àyọkà pẹ̀lú ìjúwe ṣókíBola TinubuÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáWikipedia:Àyọkà pàtàkìẸ̀sìn IslamISO 3166Ìrànlọ́wọ́:Ẹ̀kaDragon BallGbólóhùn YorùbáJapanÌgbéyàwóÀkàyéBósníà àti HẹrjẹgòfínàHọ́ng KọngAlbáníàGírámà YorùbáOṣù KàrúnWikipediaMóldófàÈdè InterlingueISO 3166-1Èbúté:Àkóónú/Àwọn èbútéFáìlì:Edit-find-replace.svgGúnugúnÀdàkọ:Àwọn orílẹ̀-èdè EuropeÀwọn GríìkìNàìjíríàWikipedia:TutorialẸ̀ka:Àwọn ọjọ́ìbí ní 19451518YorùbáEurope.mpOduduwaIṣẹ́ Àgbẹ̀Wikipedia:Àwọn àyọkà dáradáraÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáẸ̀sìnGúúsù-Ìlàòrùn ÁsíàÀríwá Amẹ́ríkàBẹ̀lárùsWikipedia:Ìtọ́nisọ́nàÌwé Àṣẹ Aṣàlàyé Ọ̀fẹ́ GNUÌtòràwọ̀Fáìlì:Ogun2.jpgBogotáIndonésíàISO 4217Èbúté:IgbesiayeÌrànwọ́:Báwo lẹṣe le ṣàfikún àwòrán s'órí ojúewéHTML