Parisi (Faransé: Paris) jẹ́ olúìlú orílẹ̀-èdè Fránsì àti ìlú tó tobijulọ nibẹ.
Àwọn ibi tó lajú níbẹ̀ gba ìlẹ̀ tó tóbi tó 105.40 km² pẹ̀lú olùgbélú 2,220,445 ní ìkànìyàn ọdún 2014.
Parisi Paris | ||
---|---|---|
The Eiffel Tower (foreground) and the skyscrapers of Paris's suburban La Défense business district (background). | ||
| ||
Population | 2,203,817 | |
Website | paris.fr |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Parisi, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.