Tòmátò ní irúgbìn tó po ti o si kéré.
Ó da fún ara wa. Tí ó bá ti pón ó ma n pupa, bi ósͅe n pón lósì ma ma tóbi. Orísͅìrisì tòmátò ló wà ní àgbáyé. Wón ma n pe tòmátò ni èso nítorí pé ó ní ìrúgbìn tó pòͅ. Sͅùgbóͅn àwoͅn ènìyàn ma n pé tòmátò l’ágbàye ni èfóͅ, wóͅn sì dèͅ má n se bi èfóͅ.
Tòmátò je eso kan ti a fi maa n se obe. Ti o ba pon tan, kii pe ra nitori naa, awon oloja maa n fe tete ta a tan. Ile Hausa ni gbigbe tòmátò wopo si ju ni ile Naijiria.
Wiki Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Solanum lycopersicum |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Tòmátò, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.