John Lewis: Olóṣèlú

John Robert Lewis (Oṣù Èrèré 21, 1940 – Oṣù Agẹmọ 17, 2020) jẹ́ olósèlù ọmọ orílẹ̀-èdè America, àti ajìjà gbara tí ó jẹ́ asojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Goeorgia láti ọdún 1987 sí ọdún 2020 tí ó fi di olóògbé.

John Lewis
John Lewis: Olóṣèlú
Member of the U.S. House of Representatives
from Georgia's 5th district
In office
January 3, 1987 – July 17, 2020
AsíwájúWyche Fowler
Arọ́pòVacant
3rd Alága igbimọ akékọ̀ álá'laafià
In office
June 1963 – May 1966
AsíwájúCharles McDew
Arọ́pòKwame Ture
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
John Robert Lewis

(1940-02-21)Oṣù Kejì 21, 1940
Troy, Alabama, U.S.
AláìsíJuly 17, 2020(2020-07-17) (ọmọ ọdún 80)
Atlanta, Georgia, U.S.
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic
(Àwọn) olólùfẹ́
Lillian Miles
(m. 1968; died 2012)
Àwọn ọmọJohn-Miles Lewis
EducationAmerican Baptist College (BA)
Fisk University (BA)
WebsiteHouse website

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀.

Ẹ̀gbẹ́ Troy, Alabama ni wọ́n bí John Robert Lewis sí ní oṣù Èrèré 21, 1940. Òun ni ọmọ kẹ́ta nínú ọmọ mẹ́wàá tí Willie Mae àti Eddie Lewis bí. Àgbẹ̀ ayálégbé tí ó máa ń fi erè oko rẹ̀ sanwó ilé ní àwọn òbí John ní abulé Pike County, Alabama, èyí tí Troy jẹ́ orílẹ̀-èdè rẹ̀..

lGẹ́gẹ́ bí ọmọdé, wu Lewis láti jẹ́ oníwàásù. Ní ìgbà tí ó wà ní ọmọ ọdún márùn-ún ní ó ti bẹ̀rẹ̀ sí ní máa wàásù fuh àwọn edìyẹ tó wà ní oko wọn. Lewis ní àǹfàní àti bá wọn aláwọ̀ funfun sọ̀rọ̀ nígbà tí ó wà ní kékeré, nígbà tí ó pé ọmọ ọdún mẹ́fà, aláwọ̀ funfun méjì péré níkàn ló ti bá sọ̀rọ̀. Ohun tí ó ṣẹlẹ̀ ni pé àwọn aláwọ̀ dúdú ni ó pọ̀ jù ní ibi tí wọ́n ń gbé, àgbẹ̀ sì ni àwọn ebí rẹ̀. Ó ṣe àpèjúwe ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní ìlé-ìwé kékeré tí kò jìnà sí ilé òun. Rosenwald School ni orúkọ ilé-ìwé ọ̀hún, ìlé-ìwé yìí nìkan ni ilé-ìwé tí wọ́n ní agbègbè wọ́n.

Itokasi

S

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

4363 SergejMemphisOlu JacobsÀkójọ àwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríà bíi ìpọ̀síènìyànẸ̀tọ́-àwòkọÁljẹ́brà onígbọrọEwìJaime LusinchiAta ṣọ̀mbọ̀Kọ̀mpútà.cdLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Àkúrẹ́IrinYemojaÀríwáMandy PatinkinQLẹ́tà Àìgbẹ̀fẹ̀Odunlade AdekolaDélé Mọ́mọ́dùÀṣàVDynamic Host Configuration ProtocolÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣunAfeez OwóAfghanístànRepublican Party (United States)Nigerian People's PartyFránsìISO 8601Fúnmiláyọ̀ Ransome-KútìGoogleJay-Jay Okocha22 AprilOSI model28 MarchApágúúsù ÁfríkàAdekunle GoldCD-ROMAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ido-OsiIllinoisHilary SwankIfáÀgbékalẹ̀ Ẹ̀kọ́Adolf HitlerAaliyah23 AugustLev BùlgáríàMarc FleurbaeyOjúAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéÀwọn Ìdíje ÒlímpíkìQueen's Counsel22 FebruaryÀwọn Ìpínlẹ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàBrómìnìÀwùjọSudan1633 ChimayDiadumenian25 JulyJBIGGuinea-BissauAdrien BrodyJennie Kim🡆 More