Ata ṣọ̀mbọ̀ tàbí (chili) .
Ata ṣọ̀mbọ̀ ni wọ́n ma ń lo láti lè jẹ́ kí ónjẹ ó ta lẹ́nu. Èròjà (Capsaicin) ni ó ma ń fún ata ṣọ̀mbọ̀ ní agbára láti ṣe iṣẹ́ títa lẹ́nu.
Ata ṣọ̀mbọ̀ lò ni ó ṣẹ̀ wá láti orílẹ̀-èdè Mẹ́síkò . Ata ṣọ̀mbọ̀ lò tan kalẹ̀ àgbáyé láti ilẹ̀ Mẹ́síkò látàrí ìdòwòpọ̀. Wọ́n máa ń lò ó fún oúnjẹ sísè àti òògùn ìbílẹ̀.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ata ṣọ̀mbọ̀, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.