Facebook jẹ́ ìkànnì abánidọ́rẹ̀ẹ́ lórí afẹ́fẹ́ ẹ̀rọ ayélujára.
Ó jẹ́ ìkànnì tí lè ní àǹfààní sí láti orí foonu alagbeka, ẹ̀rọ kọ̀m̀puta tábìlì àti èro komputa agbelowo tí ó ní àmúmọ̀ láti já lú ayé lórí afẹ́fẹ́. Ilé Iṣẹ́ tí ó ń ṣe kòkárí rẹ̀ gúnwà sí Menlo Park, California, lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ọ̀gbẹ́ni Mark Zuckerberg ní ó ṣẹ̀dá rẹ̀ lọ́dún 2004. . Alefi Facebook fòrò ránsé si olùmúlò Facebook miran, a sì tún le fi Facebook fi foto àti fidio ránsé sawon òré wa.
Facebook%2C_Inc._Logo_2019.svg | |
Type | Public |
---|---|
Area served | Worldwide |
Key people |
|
Industry |
|
Products | |
Revenue | ▲ US$55.838 billion |
Operating income | ▲ US$24.913 billion |
Net income | ▲ US$22.111 billion |
Total assets | ▲ US$97.334 billion |
Total equity | ▲ US$84.127 billion |
Employees | 43,030 |
References: |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Facebook, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.