Aymara
Àpapọ̀ iye oníbùgbé |
---|
2.0 million |
Regions with significant populations |
Bolivia (1,462,286) |
Èdè |
Aymara, Spanish |
Ẹ̀sìn |
Catholicism adapted to traditional Andean beliefs |
Ẹ̀yà abínibí bíbátan |
Quechuas |
Omo egbé Quechumaran ni Aymara. Quechumaran fúnrarè náà jé omo egbé fún àwon èdè Andea-Equatorial. Àwon tí ó ń so àwon èdè wònyí lé díè ní mílíònù méjì (2.2.million). Púpò nínú àwon tí ó ń so wón wà ní Bolivia (1.8 million) ó dín díè ní mílíònù méjì. Wón tún ń so àwon èdè wònyí ní Peru àti apá kan Argentina. Àkótó Rómáànù ni wón fi ń ko ó sílè. Ní ìgbà kan rí, Aymara jé èdè kan tí ó se pàtàkì ní ààrin gbùngbùn Andes tí wón jé apá kan Énípáyà Inca (Inca Empire)
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Aymara, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.