Tina Turner

Tina Turner (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Anna Mae Bullock; tí wọ́n sì bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù November, ọdún 1939 - 2023) jẹ́ akọrin àti òṣèré ará Amerika tí iṣẹ́ rẹ̀ gbajúgbajà.

Ó gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ, bẹ́ẹ̀ sì ni iṣẹ́ rẹ̀ nínú orin rock ti jẹ́ kí àwọn kan ó pè é ní "Queen of Rock 'n' Roll". Turner bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ pẹ̀lú ọkọ rẹ̀, ìyẹn Ike Turner, gẹ́gẹ́ bíi ọmọ ẹgbẹ́ olórin Ike & Tina Turner Reuve. Àwọn ènìyàn sì tẹ́wọ́ gbà wọ́n látàrí àwọn orin wọn bíi "River Deep, Mountain High" àti "Proud Mary". Nínú ìtẹ̀jáde ìwé tó ti sọ ìtàn nípa ara rẹ̀, nínú Tina (1986), Turner ṣàfihàn àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ńlá tí ojú rẹ̀ rí látàri ìkọlù láti ọdọ ọkọ rẹ̀, ṣáájú ìpínyà wọn ní ọdún 1976 àti ìgbà tí wọ́n kọra wọn sílẹ̀ ní 1978. Lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ló pòórá nínú iṣẹ́ orin kíkọ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún, ó wá ṣàtúnkọ́ iṣẹ́ rẹ̀, èyí tó ti ṣàgbéjáde orin àdákọ rẹ̀, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Let's Stay Together", àti èyí tó gbé jáde ní ọdún 1984 tó pè ní Private Dancer.

Tina Turner
Tina Turner performing in the GelreDome, 1985
Tina Turner performing in the GelreDome, 1985
Background information
Orúkọ àbísọAnna Mae Bullock
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiTina Turner
Ọjọ́ìbíOṣù Kọkànlá 26, 1939 (1939-11-26) (ọmọ ọdún 84)
Nutbush, Tennessee, U.S.
Irú orinRock, pop-rock, pop, soul
Occupation(s)Singer, dancer, author, actress
InstrumentsVocals
Years active1958–2020
LabelsEMI, United Artists, Capitol, Parlophone, Virgin
Associated actsThe Ike & Tina Turner Revue

Iṣẹ́ rẹ̀ nínú orin kíkọ mu wọ inú eré ṣíṣe, èyí tó sì bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ẹ̀dá-ìtàn ńlá-ńlá bíi The Acid Queen nínú fíìmù Tommy tiọdún 1975, àti àfihàn rẹ̀ nínú Sgt. Pepper's Lonely Hearts Club Band. Ó ṣe ẹ̀dá-ìtàn kan láti ṣe ìdàkejì Mel Gibson bíi Aunty Entity nínú Mad Max Beyond Thunderdome inú èyí tó gba àmì-ẹ̀yẹ NAACP Image Award for Outstanding Actress in a Motion Picture. Ó tún farahàn nínú fíìmù ti ọdún 1993 kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Last Action Hero.

One of the world's most popular entertainers, Turner has been called the most successful female rock artist and was named "one of the greatest singers of all time" by Rolling Stone. Her combined album and single sales total approximately 180 million copies worldwide. She has sold more concert tickets than any other solo music performer in history. She is known for her energetic stage presence, powerful vocals, career longevity, and widespread appeal. In 2008, Turner left semi-retirement to embark on her Tina!: 50th Anniversary Tour. Turner's tour became one of the highest selling ticketed shows of 2008–2009. Turner was born a Baptist, but converted to Buddhism and credits the spiritual chants with giving her the strength that she needed to get through the rough times. Rolling Stone ranked her at 63 on their 100 greatest artists of all time and considers her the "Queen of Rock and Roll".




Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

USA

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Èdè FínlándìPópù Pius 11kÀwọn Òpó Márùún ÌmàleIÀríwá Amẹ́ríkàJésù1490 LimpopoAdaptive Multi-Rate WidebandOperating SystemMaseruPornhubÀdírẹ́ẹ̀sì IPOṣù Kínní 31Guinea-BissauÀkójọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ NàìjíríàÀgbérò PythagorasÈdè JavaAustrálíàẸ̀sìnÌgbéyàwóÌjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020New JerseyÌpínlẹ̀ ÒgùnAtlantaCalabarISO 3166-1 alpha-2Ogun Àgbáyé KìíníFilipínìWikipediaOpeyemi AyeolaÌṣèlú ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàlJẹ́mánìKarachiPierre NkurunzizaWalter MatthauYul EdochieMons pubisHugo ChávezPópù Benedict 16kCaracasOwe YorubaOṣù KejìWÀwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáỌjọ́ RúSalvador AllendeBarbara SokyPakístàn2024Ìsirò StatistikiOmiEthiopiaOlóṣèlúẸ̀lẹ́ktrọ́nùJakarta🡆 More