Olúìlú

Oluilu je ilu ti ijoba orile-ede kan fi se ibujoko.

O tun le tumo si Ilu ti o Ba tobi ju lo, tabi ti o se pataki Ju lo Ni Agbegbe, Orile-Ede, Tabi Ipinle kankan. Fun Apere, Awon Olu Ile ti o se Pataki Julo Ni Aiye Je New York, Ni Orile Ede Amerika, ati London ni orile Ede awon Geesi. Ni Ile Erekusu{Continent} Africa , Ilu Eko Lagos Je Olu Ilu Iwo-Oorun Afrika, Beeni Nairobi ni Orile Ede Kenya ati Addis ababa ni Orile Ede Ityopiya, Je Olu Ile Ni Apa Ila-Oorun, Ni Guusu-Afrika, Ilu Johannesburg ni Orile Ede Guusu Africa Ni Olu Ilu-u Guusa-Afrika, ati Gbogbo Afrilka pelu, Nitori wipe Ilu Johannesbuurg Ni O Ni Idagbasoke ati Itesiwaju Julo Ni Eya Owo sise, Idanilaraya, Asa, Iseda Ohun elo, ati bee bee lo ni Afrika. Ni Ariwa Afrika, Ilu Casablanca ni Orile Ede Morocco, Cairo ni Ijybiti/Egypt, ati Algiers ni Algeria, Je Olu-Ilu ni ona tiwon.

Olúìlú
Oluilu


Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Maya AngelouPornhubTáyọ̀ AwótúsìnBoolu-afesegbaAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ BidaVCUniform Resource LocatorÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàAlbert EinsteinJoel McHale918 IthaGEuropean UnionUDeutschlandliedRihannaẸranISO 6166ISO 31-9Àjọ MAMSERISO 1000LíbyàIslàmabadChristiane Chabi-Kao.ukISO 19011David CameronÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáAlizé CornetISO 10303-21ISO 5776Ọ̀rọ̀ ìṣeÍndíàISO 7736ISO 8601ISO 843Ìwé-òfin Ìbágbépọ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàG8Vladimir PutinÈṣùÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáBòlífíàLouis PasteurIrinOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́2019 wiwo ile-iwe ni EkoÀdánidáISO/IEC 17024ISO 639-2.stISO 13584Frederik Willem de KlerkGregor Mendel.gbDelhiMandy MinellaBrazzavillePetra CetkovskáISO/IEC 38500ECMAScriptISO/TR 11941Mons pubisISO 639-3(9981) 1995 BS3Plateau StateISO 6438New YorkÈlòISO 10962🡆 More