Àkàyé

Àkàyé èyí ni kíkà àpilẹ̀kọ kan ní àlàyé yálà fún ìdánwò, bí ó bá jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ tàbí fún ìgbádùn ara ẹni.

Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ní ìṣòro ma ń dojúkọ àwọn olùkó láti kọ́ àwọn ọmọ ní àkàyé. Lára irú àwọn ìṣòro tí ó ma ń wáyé nínú ìwé kíkà ní wi pé ọ̀pọ̀ akẹ́kọ̀ọ́ lè dá ìró mọ̀ yàtọ̀ sí ara wọn. Ní ọ̀pọ̀ ìgbà ni ó tún jẹ́ wípé ọkàn àwọn akẹ́kọ̀ọ́ kìí sábà sí nínú ohun tí wọ́n ń kà, eléyí yóò fa ìṣòro àti lè dáhun ìbéèrè tí ó bá wà lórí àkàyé bẹ́ẹ̀. Olùkọ́ tí ó fẹ́ kọ́ àkàyé pàá pàá gbọ́dọ̀ jẹ́ olùkọ́ tí ó lè sọbèdè Yorùbá dára dára, tí ó sì pegedé nínú rẹ̀, tí ó si jẹ́ ẹni tí ó mọ òwe àti ìjìnlẹ̀ ọ̀rọ̀ tí ó wà nínú èdè Yorùbá. Olùkó tún gbọ́dọ̀ ko àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní àwọn nkan wònyí (a) Kíkà ìwé fún ìtumò (b) Ọgbón íkèwe (d) Ọgbón ibeere (e) Ọgbón ìdáhùn (e)Kíko Akẹ́kọ̀ọ́ ní Òrò àti Ìtumò. Wàyí o, láti wa kó àkàyé gan-an-gan, olùkó níláti gbẹ́ àwọn ìgbésì wònyí:

  • Kíkà ìbí àyokà fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́
  • Pípé ọ̀kan lára àwọn akẹ́kọ̀ọ́ láti ka àyokà
  • Dídáhùn àwọn ibeere pèlú ohùn ẹmu
  • Gbígbà àwọn ìdáhùn sílè nínú ìwé won.
  • Gbígbà ìwé àwọn akẹ́́kọ̀ọ jó fún ìfówósí
  • Lílò àwọn fokabulari titun ni òrò.

Àwọn Ìtọ́ka sí

Tags:

Yorùbá

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Marcelo Azcárraga PalmeroISO/IEEE 11073ISO/IEC 7813ISO 31-7Gírámà YorùbáISO/IEC 27006Owe YorubaÈdè ÁrámáìkìRELAX NGCommon CriteriaBrusselsISO 16750ISO/IEC 7816Kárbọ̀nù27 NovemberCelestial Church of ChristISO 11170WikipediaISO/IEC 8859Èdè GermanyIndonésíàSeychellesISO 9126Pópù Felix 3kHilary SwankÒrìṣà EgúngúnISOMogadishuISO 14651Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèISO 9362.gtISO 13406-2ISO 18245Althea Gibson6 FebruaryPennsylvaniaGoogleAbẹ́òkútaISO 31-1Petra CetkovskáGregor MendelÀrún èrànkòrónà ọdún 2019Julius Wagner-JaureggÈdè Lárúbáwá15107 ToepperweinÌgbéyàwóÀsìá ilẹ̀ ÍslándìDelhiKikan Jesu mo igi agbelebuNọ́rwèyÀrokòAmina BilaliBrazzavilleLíbyàBurkina FasoBùrúndìÈlòIfáOperating System.liJoel McHaleISO/IEC 27007Kuala LumpurUniform Resource LocatorẸkún ÌyàwóWiki CommonsỌbàtáláFederalismPablo Picasso.bg🡆 More