Àdájọba tabi Ìdọ́bajẹ (monarchy) je iru ijoba kan nibi ti gbogbo agbara oloselu wa patapata tabi ni oloruko lowo enikan tabi awon eyan kan.
Gege bi ohun oloselu, oludajoba ni olori orile-ede, won wa nipo yi titi di igba ti wo ba ku tabi sakuro lori ite, be sini "o je yiyasoto kuro lodo gbogbo awon omo egbe orile-ede miran." Eni toun solori ijoba adajoba ni aunpe ni adobaje tabi oludajoba. Iru ijoba yi lo wopo laye nigba ijoun ati oju dudu.
Lowolowo, awon orile-ede 44 ni won ni oludajoba gege bi awon olori orile-ede, 16 ninu won je Ile Ajoni ti won gba Queen Elizabeth II gege bi olori orile-ede won.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Àdájọba, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.