Ìrẹsì

Ìrẹsì jẹ́ èso irúgbìn ohun ọ̀gbìn tí gbogbo ènìyàn ma ń jẹ jákè-jádò orílẹ̀ àgbáyé, pàá paa jùlọ ní ilẹ̀ Asia.

Ohun ọ̀gbìn yí jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú ohun ọ̀gbìn óúnjẹ tí wọ́n pèsè jùlọ ní àgbáye ní iye ( 741.5 mílíọ́nù tọ́ọ̀nù ní ọdún 2014), lẹ́yìn Ìrèké àti àgbàdo.

Ìrẹsì
Double-headed rice, illustration from the Japanese agricultural encyclopedia Seikei Zusetsu (1804)
Ìrẹsì
A mixture of brown, white, and red indica rice, also containing wild rice, Zizania species
Ìrẹsì

Nígbà tí wọ́n ma ń lo ìrèké àti àgbàdo fún ìpèsè oríṣríṣi nkan, yàtọ̀ sí jíjẹ lásán bíi ti ìrẹsì.

Oríṣríṣi ìrẹsì ló wà, irúfẹ́ èyí tí ó bá hù ní agbègbè kan ma ń dá lórí ilẹ̀ àti ojú ọjọ́ agbègbè náà.

Ìrẹsì
Cooked brown rice from Bhutan
Ìrẹsì
Jumli Marshi, brown rice from Nepal
Ìrẹsì

.

Àwọn Ìtọ́ka sí

Tags:

AsiaÀgbàdoÌrèké

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Èdè23 AprilStuttgartÌpínlẹ̀ Òndó.na18946 MassarISO 3166.af24 OctoberÁljẹ́brà onígbọrọÈdè ÍtálìAgbon17 AprilBórọ̀nùKing's CollegeChika OduahLítíréṣọ̀AnschlussOsorkonKòréà Àríwá7 March1972 Yi XingÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáOṣù KejìOrílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ ṢáínàTallinn3254 BusWọlé SóyinkáSaint PetersburgKóstá RikàAmiri BarakaÒrùnItan Ijapa ati AjaÀsìá ilẹ̀ Kánádà8 OctoberOSI modelInáEconomicsHawaiiÀwọn Ẹ̀ka-èdè Yorùbá.fmÀkójọ átọ̀mùJuliu KésárìAustrálíàÌbálòpọ̀RáràFrançois FillonB.L. AfakiryeCliff Robertson.biJames CagneySheik Muyideen Àjàní BelloKenneth ArrowÍsráẹ́lìWolfgang PaulInternetVictor AnichebeAminu Ado BayeroÈdè IjọRonald ColmanRonald ReaganJennifer LopezLéon M'baLèsóthò7082 La Serena🡆 More