Ọba

Ọba jẹ́ ọkùnrin tí ó ń ṣolórí Ìlú ilẹ̀ tàbí orílẹ̀-èdè nítorí wípé ó lẹ́tọ̀ọ́ láti wà nípa adarí.

O le je taara lati inu ebi re tabi nitoripe ebi re lokan. Opo awon ni ile Yoruba lori bayi. Won ni awon afọbajẹ ti won gbimo ibo ni tabi inu ebi wo ni oba to kan yio ti wa. Ni Europe oba n je lati inu ebi kanna. Yio gori ite taara lati odo bàbá tabi ìyá re.

Ọba
Ọba Ataọ̀jà ilẹ̀ Yorùbá

Iyawo oba ni a n pe ni ayaba tabi ayaoba. Ni Europe obìnrin yi le gun ori ite ti oba ba ku, eyi ko je be ni ile Yoruba nibi ti obinrin ko le di oba.

Ti olori orile-ede kan ba je oba a n pe iru ijoba yi ni idobaje, ti oba na si n je adobaje.


Itokasi

Tags:

BàbáEuropeYorubaÌlúÌyáỌkùnrin

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Idi Amin DadaMa Ying-jeouISO 31D. O. FagunwaAlain DelonFriedrich HayekẸyọ tíkòsíEminemÒrò àyálò YorùbáTennessee2434 BatesonAmẹ́ríkà LátìnìÀwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáKáíròLos Angeles1588 DescamisadaAaliyahAlice BradyInternetÌwé ÌfihànMargaret ThatcherCreative CommonsOduduwaFrançois DuvalierBobriskyNetherlandsBob McGrathÒkun ÍndíàÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáQueen (ẹgbẹ́ olórin)Abidi BrailleKanayo O. KanayoÈṣùISO 639-2GoogleOrílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ ṢáínàSkopjeMicrosoftIsraelQuincy JonesÀgbájọ fún Ìdènà àwọn Ohun Ìjagun Ògùn OlóróFemi GbajabiamilaCamillo Benso, conte di CavourLinda IkejiAkanlo-edeMiguel MiramónOmahaGore VidalEwìKùránìOwe YorubaKambodiaChris RockInstagramAcehQueen's CounselThe NetherlandsÈdè LátìnìThomas AquinasPópù Alexander 6k🡆 More