Akanlo-Ede

Àkànlò-èdè ni ìpèdè tàbí ìṣòro ni ṣókí ṣókí tí ó kún fún ìjìnlẹ̀ ọ̀rọ̀ tí ìtumọ̀ rẹ̀ sì farasin.

A ma n fi àkànlò-èdè ṣe àgbékalẹ̀ ọ̀pọ̀ ọ̀rọ̀ sínú gbólóhun kan ni ṣókí nínú èdè Yorùbá. Àkànlò-èdè jẹ́ lílo ọ̀rọ̀ tàbí awẹ́-gbólóhùn lọ́nà tó jinlẹ̀ tí ìtumọ̀ rẹ̀ yàtọ̀ sí ìtumọ̀ òrèfé. Oun ni ìpèdè tí gbólóhùn inú rẹ̀ kò ní ǹǹkankan ṣe pẹ̀lú ìtumọ̀ rẹ̀.


Ìwúlò rẹ̀

Àkànlò-èdè wúlò púpọ̀ fún elédè Yorùbá l'ọ́pọ̀lọpọ̀ nígbà tí wọ́n bá fẹ́ pẹ́ ọ̀rọ̀ kan sọ. Àpẹẹrẹ:

  • Júbà ehoro
  • Gbèkurujẹ l'ọ́wọ́ ẹbọra
  • Ṣe àyà gbàngbà
  • Fárígá
  • Fi àáké kọ́rí
  • F'apá jánú
  • Jẹ orí ahun atbbl.

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

Èdè Yorùbá

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Àjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020ISO 3166PrussiaSimidele AdeagboÌránì28 MarchFáwẹ̀lì Yorùbá.bnVladimir PutinÀkójọ àwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríà bíi ìpọ̀síènìyànGiya KancheliÀdírẹ́ẹ̀sì IPÌbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kánÀgbáyé.geStuttgartMuscat23 OctoberÌkéde Akáríayé fún àwọn Ẹ̀tọ́ ỌmọnìyànSérbíà àti MontenégròOhioGlobal Positioning SystemIṣẹ́ Àgbẹ̀Frederick LugardOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìRilwan AkinolúWikiArewa 24Herbert Macaulay.cmPópù Felix 3kMadagásíkàYinusa Ogundipe Arapasowu ILáọ̀sLev BùlgáríàMandy PatinkinÈdè YorùbáPyongyangJuliu KésárìRenée ZellwegerFàdákàolómiAminu Ado BayeroIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanÈdè FaranséÀàrẹ ilẹ̀ NàìjíríàRichard NixonWaterFestus KeyamoNamibiaSílíkọ́nùRẹ̀mí ÀlùkòHamburgÌgbéyàwóOṣù KejìJúpítérìAlfonso García RoblesEré ÒṣùpáGbólóhùn YorùbáTaofeek Oladejo ArapajaFirginiaMavin RecordsỌrọ orúkọWerner FaymannGÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáDoris SimeonAfghanístànAnschlussCleopatraÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ Yorùbá🡆 More