Herbert Samuel Heelas Macaulay (November 14, 1864—May 7, 1946) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Ọmọ-ọmọ Bíṣọọ́ọ̀bù Samuel Ajayi Crowther ní Herbert Macaulay jẹ́. A bí i ní ọdún 1864. Ó gboyè ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ẹ̀rọ lórílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ó dá ẹgbẹ́-òṣèlú sílẹ̀ lọ́dún 1923. Ó kú ní ọdún 1946 níbi ti ó ti n ṣe ìpolongo ìbò.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Herbert Macaulay, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.