Àwọn Òpó Márùún Ìmàle

Àwọn Òpó Márùún Islam (Arabic: أركان الإسلام) ni a n pe awon ojuse marun to se dandan fun gbogbo musulumi.

Awon ojuse wonyi ni:

  • Shahada (ijẹrisi igbagbo ninu ọkan Olorun ati pe anọbi muhammad ẹrusin ati ojiṣẹ rẹ ni nṣe),
  • Irun (adura ojoojumo fún àwọn ada yanrí wakati máàrún),
  • Itọ ọrẹ anu Zakat jẹ ọrọyàn lẹ kan lọdun fún gbogbo musulumi ti o ba ní owo nipa mọ Ka odindin ọdún tí bukata kan ko kọlù. Ida kàn ogójì ni yi o fi tọ ọrẹ (ọpọlọpọ Musulumi ma n saba yọ zakat wọn losu Ramadan nitori lada to pọ ninu oṣu náà)
  • Awe osu Ramadan jẹ awẹ ọrọ yan nigba osu Ramadan fún gbogbo musulumi, ati
  • Haji (irinajo lo si Mekka, ibi ti Masjid al-Haram (Mosalasi Mimo) wa, to je mosalasi to gbajumo julo ninu Imale).


Itokasi

Tags:

Muslim

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Yuri AndropovOlaitan YusufTina TurnerAmerika (orile)Họ́ng KọngJerúsálẹ́mùẸṣinJosephine BakerFrench PolynesiaKùránìTsílèÌwọòrùn ÁfíríkàÀwọn Erékùṣù KáímànAyéJames D. WatsonỌ̀rànmíyànDavid CameronOrílẹ̀-èdè olómìniraWilly BrandtDenis IstominCitibankSonySurreyẸ̀sìn BúddàÌjà fẹ́tọ̀ọ́ ObìnrinDavid Lee (physicist)Beyoncé KnowlesMuammar al-GaddafiJohn WayneÀwọn Òpó Márùún IslamPresident of the United StatesWhatsappIndonésíàEre idarayaOṣéáníàÌjídìde FránsìVladimir LeninLebanonÀsà ilà kíkọ ní ilé YorùbáAfghanístàn.auRichard NixonLúksẹ́mbọ̀rgÀjẹsára ibà pọ́njú-pọ́ntọ̀East TimorSáúdí Arábíà3 NovemberJohn Maynard KeynesÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáÌlú11 AprilIndiana PacersAnna NetrebkoGuatemalaHelmut SchmidtKóstá RikàYorùbáDante AlighieriFátímọ̀ ọmọ MùhammédùÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàItálíàLangston HughesIPhoneNew York CityPópù Alexander 7kGríìsìÌwé PsalmuPhiladelphiaTashkentCouncil of EuropeFrançois DuvalierÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 201219 DecemberBósníà àti Hẹrjẹgòfínà🡆 More