Samuel Ajayi Crowther

Samuel Àjàyí Crowther (c.

1809 - December 31, 1891) jẹ́ onímọ̀ èdè Yorùbá àti Bíṣọ́ọ́bù akọ́kó fún ìjọ Anglican lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Òṣoògùn(ibi ti a pada mò si ìlú Ado-Awaye) ní ìjọba Ìbílẹ̀ Ìsẹ́yìn ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Àwọn olówò ẹrú Fúlàní kó ohun àti ìdíle rè mẹ́rú nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún méjìlá. Eléyí selè nígbà ogun abele èyà Yoruba, papaa jùlo àwon ogun ìlú Owo(1821-1829), won si padà taa fawon olówó eru Portuguese. níbi ti wòn ti gbe lo sínú okòjú omi ni odò Atlantic ti o ún lo si iwo oòrùn àgbáyé.

Samuel Ajayi Crowther
Samuel Adjai Crowther, Bishop, Niger Territory, Oct. 19 1888 (from Page, p. iii)

Awon Royal Navy's West Africa Squadron ti won un sise fun British láti fo pin sí ikonileru tú Crowther sílè. Wón ko àwon eniyan ti won tú sílè si orílè-èdè Sierra Leone. Ni Sierra lone, Ajayi fi Samuel Crowther se orúko ara rè. O si tún bèrè èkó Òyìnbó..

Ajayi di Christeni o si tún bere si ún pe Ara rè ní omo èyà Krio ni orílè-èdè Sierra Leone. O kó ìmò èdè, won si tun padà só minisita ní England, nibi TiVo pada gba àmì-èye dókítá ní Yunifásitì ìlú Oxford. O se ogbufo Ìwé adura Anglican si èdè Yoruba, o si tún sísé lórí ogbufo Bibeli láti èdè Oyinbo sí Yorùbá.

Ìdílé rè

Samuel Crowther je omo-omo Oba Abiodun, eni ti o jé baba ìyá rè. Ajayi je omo odun mejila nigba ti àwon akonileru fulani ko ohun, ìdíle rè àti àwon ara abúlé rè ni March 1821 ti wón si ta wón fún àwon olowo-eru Portuguese. Ìyá rè, Afale, eni ti a padà fún ni oruko Hannah nigba ti a se itebomi fun, aburo rè okunrin, àti awon ìdíle re wa lára awon ti wón kó. O si da wipé wón pa bàbá rè. Ayemi nigba ri wón kogun ja abúlé rè tabi léyìn ìgbà díè ti isile náà se.

Àwon British fofinde ikonileru gba okun Atlantic ni odún 180u, won si fi àwon omo ogun ojú omi won mu kí òfin náà wa sí imúse. Ni igbayen, orílè-èdè Spain àti Portugal si fi àyè gba kíkó ni lérú lo sí orílè-èdè Amerika. Ki okò ojú-omi náà to fi etí odò sílè lo sí orílè-èdè Amerika, àwon omo ologun odo ti Britain wo okò náà pèlú won, labé ase Captain Henry Leeke. Won tun àwon eru náà kalè, won si ko Ajayi àti ìdíle rè lo si Sierra Leone, nibi ti awon olori ibè ti fi wón si ìbi ti won o bugbe sí.

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

December 31

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

RwandaÀwọn BàhámàPrologYorubaLagos State Ministry of Science and TechnologyItan Ijapa ati AjaEarthFile Transfer Protocol17 AprilÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáÀsà ilà kíkọ ní ilé YorùbáOsita IhemeSARS-CoV-2Kọ̀mpútàLos AngelesGuinea-Bissau(7123) 1989 TT1Lẹ́tà Àìgbẹ̀fẹ̀Kọ́nsónántì èdè YorùbáRonald ColmanYinusa Ogundipe Arapasowu I.naVladimir PutinISO 128Ernest LawrenceBórọ̀nùMao ZedongNeodymiumÈdè PólándìSaint HelenaẸ̀tọ́-àwòkọBoris YeltsinÀkójọ átọ̀mùBlu-ray DiscAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéRuth KadiriOgun Àgbáyé KìíníASCIIC++Ọdún EgúngúnPópù Innocent 5kAyéÀsìkòAkanlo-edeBobriskyBill ClintonMicrosoftRihannaFestus KeyamoSukarno10 JulyPhoebe Ebimiekumo24 AprilDavid Jemibewon21 JulyEconomicsSaint PetersburgSérbíà àti MontenégròIlẹ̀ YorùbáCleopatraPhoenix🡆 More