Ọ̀rọ̀-àyálò jẹ́ ọ̀rọ̀ kan Pàtàkì tí a yá wọnú èdè Yorùbá láti inú èdè mìíràn, ó le jẹ̀ láti inú Gẹ̀ẹ́ṣì, Lárúbáwá, Haúsá àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ kí ó lè bá ohun tí wón fẹ́ mu nínú èdè won.
Àkíyèsí sí wà pé kò sí èdè tàbí àwùjọ kan tí kì í ya ọ̀rọ̀ láti inú èdè kan, bí Gẹ̀ẹ́ṣì ṣe yá ọ̀rọ̀ bẹẹ náà ni àwùjọ Yorùbá náà yá ọ̀rọ̀, bí ó sì ṣe wà káàkiri nínú gbogbo èdè àgbáyé.
Oríṣiríṣi Ọ̀nà méjì làá gbà yá ọ̀rọ̀ lò nínú èdè Yorùbá.
1) Àfetíyá
2) Àfojúyá
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Òrò àyálò Yorùbá, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.