Ìyá

Ìyá (màmá tabi mọ̀nmọ́n) ni òbí tó jẹ́ obìnrin èèyàn kan.

Ìyá àti bàbá jẹ́ òbí fún ọmọ tàbí ènìyàn kan. Àwọn Yorùbá bọ, wọ́n ní, " Ìyá ni wúrà"... Bẹ́ẹ̀ náà tún ni, " Gbẹ̀dẹ̀ bí Ogún Ìyá, aninilára bí Ogún Baba". Ìyá jẹ́ ọ̀kan gbógì tí wọn kò ṣéé fojú rénà láwùjọ, ní ìlú, Ìpínlè pàápàá jùlọ lagbaye. Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ìgbà, ìyá ló máa ń bí ọmọ fún ara rẹ̀, nígbà mìíràn ó lè gba ọmọ ẹlòmíràn bí ọmọ rẹ̀ tàbí kí ó gba ọmọ ẹlòmíràn tọ́.

Ìyá
Ìyá àti ọmọ rẹ̀

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

BàbáObìnrinÒbí

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Weimar OlómìniraAdeniran OgunsanyaÀsà ilà kíkọ ní ilé YorùbáSpéìnPólándì24 MarchDavid ToroBimbo AdemoyeHitoshi OgawaHenry Hallett DaleGbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdèBaktéríàNyma Akashat ZibiriISO 4217ToyotaLebanonLouis 14k ilẹ̀ FránsìÈdè RomaníàBurkina FasoWikiẸ̀wádún 20101 JulyOperating System26 MarchISO 3166Hashim ThaçiKarachi2024Írẹ́lándìÀwọn ọmọ AzerbaijanAlaskaEden HazardC++AtlantaMobolaji AkiodeLátfíàD. O. FagunwaIgbó OlodùmarèOrílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ ṢáínàTorontoPornhubKatsura TarōKùrìtíbàLéon BlumRobert Walpole5 Oṣù KẹtaBùrúndì14 Oṣù Kẹta23 JulyÈdè OccitaniSudanÀrùn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn EbolaSheik Muyideen Àjàní BelloÈdè ÍgbòÈdè IrelandKòréà Àríwá13 December22 Oṣù KẹtaÈdè ṢáínàÌpínlẹ̀ DeltaEuropeÒgún LákáayéMẹ́ksíkò🡆 More