Àgbàdo: Odun,aleseje,ale fi se ogi fun eko mimu

Àgbàdo (Látìnì: Zea mays) ni ó jẹ́ óuńjẹ jij́ẹ oní hóró tí àwọn ènìyàn ilẹ̀ apá Gúúsù ilẹ̀ Mexico ṣe àwárí rẹ̀ ní ǹkan bíi egberun mewa odun seýin..

Igi àgbàdo ma ń yọ ewé sooro, tí ó sì ma ń yọ ìrùkẹ̀rẹ̀ ní ọwọ́ òkè èyí tí ó ma ń ṣe atọ́nà fún yíyọ ọmọ àgbàdo . Àwọn onímọ̀ sáyẹ́nsì fẹ́ràn láti máa pèé ní Maize (àgbàdo) nítorí wípé orúkọ yí ni ó gbajúmọ̀ jùlọ fún irúfẹ Oúnjẹ oníhóró yí, tí ó sì ní it̀umọ̀ oríṣiríṣi lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn ní orílẹ̀ àgbáyé.

Àgbàdo
Àgbàdo: Odun,aleseje,ale fi se ogi fun eko mimu
Illustration showing male and female maize flowers
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Ìjọba: Ọ̀gbìn
Clade: Vascular plant
Clade: Flowering plant
Clade: Monocotyledon
Clade: Commelinids
Ìtò: Poales
Ìdílé: Poaceae
Ìbátan: Zea (plant)
Irú:
Z. mays
Ìfúnlórúkọ méjì
Zea mays
Àgbàdo: Odun,aleseje,ale fi se ogi fun eko mimu
Zea mays "fraise"
Àgbàdo: Odun,aleseje,ale fi se ogi fun eko mimu
Zea mays "Oaxacan Green"
Àgbàdo: Odun,aleseje,ale fi se ogi fun eko mimu
Zea mays "Ottofile giallo Tortonese”



Itokasi

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Frederica WilsonJosé Manuel PandoISO 9985MáàdámidófòJPEG XRMandy MinellaRosa LuxemburgISO 14644-3TallinnISO/TR 11941Nọ́rwèyISO/IEC 8859-5LíbyàBrasilGeoff Pierson.maMarcelo Azcárraga PalmeroISO/IEC 8820-5Ogun Àgbáyé KìíníTẹlifóònùBrusselsDavid WoodardTivISO 3166-2ISO/IEC 7813TogoBaghdadÌwé EksoduOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìIndonésíàGánàIpa ajakaye arun COVID-19 lori ona ati asa adayeba29 NovemberZAmòfinỌjọ́Ẹ̀sìnÀdéhùn VersaillesAli NuhuBrigitte Bardot2019 wiwo ile-iwe ni EkoISO/IEC 11404Whirlpool (cryptography)ISO 9984DelhiISO 31-4ISO 4ISO 15706-2Iṣẹ́ ọnàISO 13485SARS-CoV-2Àsìá ilẹ̀ SingaporeÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàKarl MarxAaliyahÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 2004ISO 13406-2Dẹ́nmárkì.ttOrúkọ YorùbáWiki918 IthaISBNISO 7002🡆 More