Mathimátíkì: MATIMÁTÌSÌ

Mathematiki tabi Ìmọ̀ Ìsirò jẹ́ èyí t'on jẹ mo nipa ọ̀pọ̀iye (quantity), nipa òpó (structure), nipa iyipada (change) ati nipa ààyè (space).

Idagbasoke imo Isiro wa nipa lilo àfòyemọ̀ọ́ (abstraction) ati Ọgbọ́n ìrọ̀nú, pelu onka, isesiro, wíwọ̀n ati nipa fi fi eto s'agbeyewo bi awon ohun se ri (shapes) ati bi won se n gbera (motion). E ni awon Onimo Isiro n gbeyewo, ero won ni lati wa aba tuntun, ki won o si fi ootọ́ re mulẹ̀ pelu itumo yekeyeke.

Mathimátíkì: MATIMÁTÌSÌ
Agbègbè tí a tí nko èkó ìsirò ti ile-èkó èkósé owó ti modèle de Galton-Watson.

Mathimátíkì: MATIMÁTÌSÌ

A n lo Imo Isiro ka kiri agbaye ni opolopo ona ninu Imo Sayensi, Imo Ise Ero, Imo Iwosan, ati Imo Oro Okowo. Eyi je mo eko imo isiro to ko ti ni ilo kankan bo tileje pe o se se ki a wa ilo fun ni eyinwa ola.



Àwon Itoka si

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Masẹdóníà Àríwá22 OctoberAloma Mariam MukhtarAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifelodun, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣunJulian SchwingerJohannesburgÀṣàNancy ChartonÍslándìDynamic Host Configuration ProtocolÌmọ́lẹ̀SlofákíàKọ̀mpútàMọ́remí ÁjàṣoroÌránìStuttgartÀwọn Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ NàìjíríàDiphalliaTibetÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáEré ÒṣùpáOmi.ioUttar PradeshÈdè EsperantoPópù Innocent 5kISO 128Banky W4 JuneAmiri BarakaIṣẹ́ ọnàAma Ata AidooOṣù Kejì6 AugustOgunPhoebe EbimiekumoÌpínlẹ̀ GeorgiaOrin apalaỌbàtáláLítíréṣọ̀Sesi Oluwaseun WhinganSpéìnSókótóPópù Adrian 4kÒṣùpá16 FebruaryItan Ijapa ati AjaNkiru Okosieme2009Èdè FaranséÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáSeye KehindeOwo siseBOpen Amẹ́ríkà 1985 − Àwọn Obìnrin ẸnìkanLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Ọrọ orúkọÀàrẹ ilẹ̀ NàìjíríàIlé-Ifẹ̀Nọ́mbà tíkòsíWọlé SóyinkáÀkàyéHorsepowerLionel BarrymoreÀṢÀ ÌKÍNI NÍ ÀWÙJỌ YORÙBÁISO 8000Turkey🡆 More