Ogun

Ogun Ẹkú dédé àsìkò yìí ẹ̀yin ọmọ ogun.

Ẹ jọ̀wọ́ ẹ jẹ́kí á tún bọ̀ sọwọ́pọ̀ láti gbé ògo ilẹ̀ Yorùbá ga.Inù mi dùn púpọ̀ sí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n ẹ̀ẹ̀tí kẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n sì jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Yorùbá yálà nílẹ̀ Yorùbá tàbí ní òkè òkun bá lè bẹ̀rẹ̀ láti máa kọ́ ọ̀pọlọ̀pọ̀ nínú àwọn àròkọ wọn ní èdè abínibí wà nítorí òní kọ́ àmọ́ nítorí ọjọ́ ọ̀la kí àwọn ọmọ tí wọn kò ì tíì bí lè rí nnkan kà nípa gbogbo ohun mère mère tí ó n sẹlẹ̀ jákè jádò àgbáyé.

Ogun
Ala-ilẹ kan nibiti awọn aririn ajo ti ba ni ita ilu kekere kan.
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa ìjà jàgídíjàgan. Fún ìtumọ̀ míràn, ẹ wo: Ogun (ìṣojútùú).

Tí a bá wo àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n sẹ̀sẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sì ní máa gbérí níwọ̀n ọgbọ́n ọdún sẹ́yìn a ri wí pé púpọ̀ nínú wọn ni wọn fi èdè abínibí kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọ́n, kòsí iṣẹ́ìwádìí kan tí wọ́n se tí wọ́n kò kọ ní èdè wọn bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé èdè gẹ̀ẹ́sì ni wọ́n gbà fi se ìwádìí náà. Ó seni láànu láti máa pàdé àwọn ara ilé nílu òyìnbó kí wọ́n máa fara pamọ́ ki a máà ba pè wọ́n ní ọmọ Yorùbá.Ogún lọ́gọ̀ àwọn olùkọ́ni nílu òyìnbó ni wọ́n jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Yorùbá sùgbọ́n pẹ̀lú gbogbo akitiyan wọn kò sí ọ̀kan soso nínú isẹ́ ìwádìí wọ́n pẹ̀lú aroko tí ó wà ní èdè Yorùbá- Kí ló dé?

Ọ̀rọ́ tán lẹ́nu sùgbọ́n ó pọ̀ níkùn,

Títí di ọjọ́ mìíràn ọjọ́ ire, Emi ni tiyín ní tòótọ́, Ọmọba Onanusi Olusegun. [email protected]ó

Àkíyèsí pàtàkì - Ti ẹ bá ní ohun láti sọ nípa àròkọ yìí, ẹ̀yin náà lè bọ́sí gbàgede WIKIPEDIA.


Itokasi

Tags:

YorùbáỌmọ

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ISO 4217Carl Johan ThyseliusInternetÀsìá ilẹ̀ Bárbádọ̀sMediaWiki3016 MeuseFàájì FMAkanlo-edeCorine OnyangoMandy PatinkinOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́Ológbò8 DecemberCzechoslovakia3471 Amelin25 AprilSylvester MaduRodrigo Borja CevallosWikiChaudhry Shujaat HussainLimaPornhubAdolf HitlerÈdè YorùbáIlẹ̀ YorùbáÀjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ní àwọn Erékùṣù KánárìIṣẹ́ Àgbẹ̀KentuckyÀkọ̀mọ̀nà13 OctoberAustrálíàHéctor José CámporaAlain PoherÍndíàIrinNgozi NwosuDọ́là àwọn Erékùṣù Káímàn10650 HoutmanSigourney WeaverSpéìnLoquatGoogleRwandaÀdírẹ́ẹ̀sì IPAtlantaMọ́rísì22 FebruaryOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ BáháráìnìMpumalangaEhoroGrace EborOnome ebiKárbọ̀nùÌbálòpọ̀Juan Esteban PederneraÌgbéyàwóÌsopọ̀ kẹ́míkàNelson MandelaPópù Celestine 2kÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Brasil.gqGibraltarApá Mono🡆 More