Ìyá

Ìyá (màmá tabi mọ̀nmọ́n) ni òbí tó jẹ́ obìnrin èèyàn kan.

Ìyá àti bàbá jẹ́ òbí fún ọmọ tàbí ènìyàn kan. Àwọn Yorùbá bọ, wọ́n ní, " Ìyá ni wúrà"... Bẹ́ẹ̀ náà tún ni, " Gbẹ̀dẹ̀ bí Ogún Ìyá, aninilára bí Ogún Baba". Ìyá jẹ́ ọ̀kan gbógì tí wọn kò ṣéé fojú rénà láwùjọ, ní ìlú, Ìpínlè pàápàá jùlọ lagbaye. Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ìgbà, ìyá ló máa ń bí ọmọ fún ara rẹ̀, nígbà mìíràn ó lè gba ọmọ ẹlòmíràn bí ọmọ rẹ̀ tàbí kí ó gba ọmọ ẹlòmíràn tọ́.

Ìyá
Ìyá àti ọmọ rẹ̀

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

BàbáObìnrinÒbí

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Pierre NkurunzizaLọndọnuJapanMọ́remí ÁjàṣoroÒgún LákáayéWiki CommonsWalter MatthauOlógbòOrílẹ̀EarthLinuxAtlantaAItan Ijapa ati AjaWikiBarry WhiteGoogleXÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáVladimir NabokovLiberiaÌlúÀríwá Amẹ́ríkàOṣù KejìAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéSíńtáàsì YorùbáApple Inc.The New York TimesAli Abdullah SalehEuropeAustrálíàHTMLÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020Àjẹsára Bacillus Calmette–GuérinIlẹ̀ Ọba BeninẸyẹAjáÌṣeọ̀rọ̀àwùjọSheik Muyideen Àjàní BelloẸ̀lẹ́ktrọ́nùYIMegawati SukarnoputriLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀(213893) 2003 TN2Abdullahi Ibrahim (ológun)Saheed OsupaOṣù Kínní 152009Àwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáBobriskyAderemi AdesojiSARS-CoV-2Èdè YorùbáPópù Benedict 16kPópù Pius 11kÌbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kánIndonésíàÌsirò Statistiki🡆 More