Katherine Esther Jackson (née Scruse, orúkọ àbísọ Kattie B.
Screws; May 4, 1930) ni ìyá-àgbà ìdílé Jackson. Òhun ni ìyá Michael àti Janet Jackson àti àwọn ẹ̀gbọ́n wọn.
Katherine Jackson | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Kattie B. Screws Oṣù Kàrún 4, 1930 Clayton, Alabama, U.S. |
Iṣẹ́ | Author |
Olólùfẹ́ | Joe Jackson (m. 1949; died 2018) |
Àwọn ọmọ | 10 (incl. Michael, Janet; see below) |
Ẹbí | Jackson |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Katherine Jackson, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.