Ìyá Jésù Màríà

Màríà (èdè Aramaiki, èdè Heberu: מרים, Maryām Miriam; èdè Arabu:مريم, Maryam), ti awon omo leyin Kristi n pe ni Mariamo, Maria Wundia tabi Maria Mimo ati nigba miran Madonna, je obinrin Ju ara Nazareth ni Galilee, ti Majemu Tuntun tokasi gege bi iya Jesu Kristi.

Awon musulumi na un pe ni Maria Mimo tabi Syeda Mariam, to tumosi Màríà Ìyá Wa. Majemu Tuntun se apejuwe re bi wundia (Griiki παρθένος, parthénos). Awon Elesin Kristi gbagbo pe o loyun Jesu nipa Emin Mimo.

Màríà, Ìyá Jésù
Mary, Mother of Jesus
Ìyá Jésù Màríà
The Madonna in Sorrow, by Sassoferrato, 17th century.
Theotokos ("Mother of God")
Blessed Virgin Mary
Umm Issa ("Mother of Jesus")
Saint Mary
Bornunknown; celebrated 8 September
Diedunknown; See Assumption of Mary
Venerated inAnglican Communion
Eastern Orthodoxy
Lutheranism
Oriental Orthodoxy
Catholic Church

Recognized and honored
(not venerated) in:

Islam

Protestantism
Major shrineSee Shrines to the Virgin Mary
FeastMary is commemorated on as many as 25 different days. The most universally observed are:

25 March – The Annunciation 15 August – The Assumption (Catholicism)
15 August – The Dormition (Orthodoxy)

22 August – The Assumption Coptic-Orthodox
PatronageSee Patronage of the Blessed Virgin Mary




Itokasi

Tags:

Arabic languageAramaic languageChristiansHebrew languageJesus ChristMuslimsNew Testament

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

HypertextIrinPópù Adrian 3kWikipẹ́díà l'édè YorùbáỌ̀rànmíyànGloria EstefanTẹ́lískópùÁrktìkìParisiÌwọòrùn ÁsíàKing's CollegeZÒjòZincỌrọ orúkọSanusi Lamido SanusiÒrò àyálò YorùbáB.L. Afakirye2 JuneSunita WilliamsLa Réunion27 JuneEuro22 OctoberPOSIXÀkójọ átọ̀mùÈdè FaranséJúpítérìIfáMáàdámidófòỌ̀rúnmìlà.afJames CagneyÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàFilipínìÌlú KuwaitiÀwọn Ìpínlẹ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàVictor AnichebeQuincy JonesBobriskyQueen's CounselỌ̀rọ̀ayéijọ́unJohn MiltonLagos StateÀdírẹ́ẹ̀sì IPOrin apala.ioISO 6523CaliforniaArewa 24Àwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáMọ́remí ÁjàṣoroIléÌran YorùbáErin-Ijesha WaterfallsAloma Mariam MukhtarMalek JaziriTaofeek Oladejo ArapajaBeninLáọ̀sRáràFirginia22 FebruaryRẹ̀mí Àlùkò🡆 More