Christmas

Ọdún Kérésìmesì(tí wọ́n ń pè ní Christmas ní èdè Gẹ̀ẹ́sì) jé ayẹyẹ ọdọọdún láti ṣe àjọyọ̀ ibí àti ìwà sáyé Jésù Kristi, èyí tí ó ma ń sábà wáyé ní ọjọ́ Kàrúndinlogbin oṣù Kejìlá(Dec 25).

Bí ó tilè jẹ́ wípé àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ńṣe àjọyọ̀ yìí ní ọjọ́ Kàrún lélógún oṣù Kejìlá, àwọn Kristẹni míràn ṣe ayẹyẹ náà ní ọjọ́ míràn, bí àpẹẹrẹ, àwọn ìjọ ní órílẹ̀ èdè Armenia ṣe ajoyo náà ni ọjọ́ keje oṣù kini(Jan 6). Àwọn ìjọ míràn ní Armenia tí ó ún lo Kalenda Julian ṣe ayẹyẹ Kérésìmesì ní ọjọ́ kádinlogun oṣù Kínní ọdún(Jan 19), ọjọ́ kejìdínlógún sì jẹ́ ọjọ́ aisimi Kérésìmesì. Àwọn míràn tún ṣe ayẹyẹ yìí ní ọjọ́ kerinlelogun oṣù Kejìlá(Dec 24).

Christmas
Àwòrán ìbí Jésù.
Christmas
Ọdún Kérésìmesì
Also calledNoël, Nativity, Xmas, Yule
Observed byChristians, many non-Christians
TypeChristian, cultural
SignificanceAyẹyẹ ọjọ́ ìbí Jésù
Date
  • December 25
    Western Christianity and some Eastern churches; secular world
  • January 7 [O.S. December 25]
    Some Eastern churches
  • January 6
    Armenian Apostolic and Armenian Evangelical Churches
  • January 19 [O.S. January 6]
    Armenian Patriarchate of Jerusalem
Celebrationsìfúni lẹ́bùn, àti àpéjọpọ̀
ObservancesÌpéjọpọ̀ ní ilé ìjọsìn

Ìtàn Kérésìmesì sọ nípa àkọlé majẹmu titun inú Bíbélì, tí ó sọ nípa ibí Jesu nínú Bethlehem láti mú àsọtẹ́lẹ̀ nípa ibi rẹ̀ ṣe. .

Nígbà tí Jósẹ́fù àti Maria ìyá Jesu wọ ìlú náà, ilé ibùsùn tí wón wò kò ní ìyára, èyí mú kí wón fi ibùjẹ ẹran lọ̀ wọ́n, ilé ibuje ẹran yìí ni a bí Jesu sí, àwọn áńgẹ́lì sì kéde ibí rẹ̀ fún àwọn oluso àgùntàn, tí àwọn Olùṣọ́ àgùntàn náà sì fi ọ̀rọ̀ nípa ibí rẹ̀ lédè. Gẹ́gẹ́ ìtàn Bíbélì, a bí Jésù nígbà isejoba Herod the Great. Ìtàn ìhìn rere Luku sọ nípa bí Jósẹ́fù àti Màríà ṣe fi Nazareti(ìlú wọn) kalẹ tí wón sì wá sí Bethlehemu láti wá san owó orí. Wọ́n pẹ́ kí wọ́n tó dé Bethlehemu, ìgbà tí wón sì dé ìbè, kò sí àyè mó ní ilé igbalejo. Wọ́n fi ilé ibùjẹ ẹran lọ̀ wọ́n, wọ́n sì kalè síbè, àìpé rẹ̀ ni wọ́n bí Jesu.

Àbá oríṣiríṣi ni ó wà nípa ijọ́ tí a bí Jesu, lẹ́yìn bi ọdún ọgọrun mẹ́rin tí wón bí Jésù, àwọn ìjọ pinu láti fi ọjọ́(ayẹyẹ) náà sí Dec 25. Nígbà tí oyún Èlísábẹ́tì pé oṣù mẹ́fà, Grabrieli farahàn Maria, ó sì sọ fún pé yó lóyún. Nkan pàtàkì láti mọ̀ ni pé kì í ṣe gbogbo ìjọ àkókó ni ó fọwọ́ si fífi ọjọ́ Kàrún lélógún oṣù Kejìlá ṣe ayẹyẹ Kérésìmesì.

Ọ tún le ka èyí

Awọn ìtọ́kasí

Tags:

Jésù

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ÌjíptìPatrick Blackett, Baron BlackettApple Inc.Àríwá Amẹ́ríkàÌkéde Akáríayé fún àwọn Ẹ̀tọ́ ỌmọnìyànIndonésíàKọ̀mpútàÌhìnrere MárkùMeitneriomuAdvanced Audio CodingẸ̀sìn IslamÌgbà Ọ̀rdòfísíàIPhoneEzra OlubiGúúsù Áfríkà21 MayGbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdèYunifásítìCharlize Theron24 DecemberAlaskaÈkó9 FebruaryÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 1936Pópù Jòhánù Páúlù ÈkejìÀwọn ará Jẹ́mánìÒrùnKàlẹ́ndà GregoryÈdè Pẹ́rsíàDomain Name SystemDmitry Medvedev6 JulyẸ̀kùàdọ̀r2024GuayaquilFiẹtnámISBNInternet Relay ChatLebanonOsama bin LadenÒkun ÁrktìkìJacques MaritainMartin LutherTitun Mẹ́ksíkòGaza StripLusaka1 NovemberFidio erePaul OmuÌwé-òfin Ìbágbépọ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà1 Oṣù KínníÒmìniraÌsọ̀kan Sófìẹ̀tì10 AugustBloemfonteinFrançois AragoSiamunThalliumKòréà GúúsùISO 31-1WEarthMinskNeanderthal9 MarchLátfíà🡆 More