Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà (pípè /ˈbɒzni.ə (ænd) hɜrtsɨˈɡoʊvɨnə/ ( listen) or /ˌhɜrtsɨɡoʊˈviːnə/; Bosnian, Croatian, Serbian Latin: Bosna i Hercegovina; Bosnian and Serbian Cyrillic: Босна и Херцеговина) je orile-ede ni Guu-Apailaorun Europe, ni Peninsula Balkani.
O ni bode mo Kroatia ni ariwa, iwoorun ati guusu, Serbia ni ilaorun, ati Montenegro si guusuilaorun, Bosnia ati Herzegovina (bakanna: Bosnia-Herzegovina/Bosnia ati Hercegovina) je ku di ko je ayikanule, ayafi fun 26 kilometres (16 miles) ebado Omi-okun Adriatiki, ni ilu Neum. Abenu orile-ede na je kiki okegiga ni arin ati si guusu, ilegiga ni ariwaiwoorun, ati ile pelebe ni ariwa ilaorun. Ninu na tu ni ibi jeografi totobiju to ni ojuojo orile iloworo, to ni igba orun gbigbona ati igba otutu to ni yinyin. Eti apaguusu re ni ojuojo Mediteraneani ati ojuile pelebe.
Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà Bosnia and Herzegovina Bosna i Hercegovina Босна и Херцеговина | |
---|---|
Orin ìyìn: Državna himna Bosne i Hercegovine The National Anthem of Bosnia and Herzegovina | |
Ibùdó ilẹ̀ Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà (green) on the European continent (dark grey) — [Legend] | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Sarajevo |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Bosnian/Croatian/Serbian |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 48% Bosniak 37% Serb 14% Croat |
Orúkọ aráàlú | Bosnians, Herzegovinians |
Ìjọba | Parliamentary republic |
• High Representative | Christian Schmidt1 |
• Presidency members | Denis Bećirović2 Željka Cvijanović3 Željko Komšić4 |
Borjana Krišto | |
Independence | |
• Formed | August 29, 1189 |
• Banate established | 1154 |
• Independence lost to Ottoman Empire conquest | 1527 |
• Annexation of Bosnia by Austro-Hungarian Empire | 1908 |
• National Day | November 25, 1943 (establishing of the anti-fascist governing organ ZAVNOBIH) |
• Independence Day (from the SFR Yugoslavia) | March 1, 1992 |
• Observed | April 6, 1992 |
Ìtóbi | |
• Total | 51,129 km2 (19,741 sq mi) (127th) |
Alábùgbé | |
• 2009 estimate | 4,613,414 (120th5) |
• 1991 census | 4,377,053 |
• Ìdìmọ́ra | 902/km2 (2,336.2/sq mi) (126th5) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $29.477 billion |
• Per capita | $7,361 |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $17.133 billion |
• Per capita | $4,278 |
Gini (2007) | 30.15 medium |
HDI (2008) | ▲ 0.812 Error: Invalid HDI value · 76th |
Owóníná | Convertible Mark (BAM) |
Ibi àkókò | UTC+1 (CET) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+2 (CEST) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | 387 |
Internet TLD | .ba |
|
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.