Mons Pubis

Ní ìmọ̀ nípa ẹ̀yà ara ènìyàn, àti ní gbogbo àwọn ẹranko tí ó lè bímọ, mons pubis (tí a tún mọ̀ sí  mons, àti ní pàtó lara àwọn obìrin sí mons Venus tàbí mons veneris), jẹ́ ibi róbótó tó lọ́rá lókè pubic symphysis ti àwọn egungun pubic.

Ní ara àwọn obìrin, ó maa ń ṣarajọ sí iwájú vulva. Ó pín sí labia majora ("ètè tó fẹ̀") ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì furrow tí wọ́n mọ̀ sí pudendal cleft tí ó yí labia minora, clitoris, urethra, ojú òbò àtí àwọn ẹ̀yà míràn nínú vulval vestibule.

Mons pubis
Mons Pubis
Details
PrecursorGenital tubercle
Identifiers
Latinmons pubis
Dorlands
/Elsevier
20.htm 12541373
TAA09.2.01.002
FMA20218
Anatomical terminology

Ìtóbisí mons pubis kò rí bákan tí ó sì ní ṣe pẹ̀lú ìwọn kẹ́míkà ìtọ́sọ́nàn ara àti ọ̀rá ara, tí ó sì ṣeé rí dáradára lára àwọn obìrin.  Lẹ́yìn tí obìrin ba ti bàlágà, irun máa ń bo ojú ẹ̀ tí ó sì máa ń fẹ̀.  Àwọn ọ̀rá inú mons pubis maa ń gbẹgẹ́ sí estrogen, tí ó sì máa ń fa ìṣarajọ òkìtì tí obirin ba ṣẹ̀ṣẹ̀ ń bàlágà. Èyì má a ń ti iwájú labia majora sí ìta kúrò nínú egungun pubic. bẹ́ gẹ́gẹ́,mons pubis má a ń sábà hàn dáradára tí estrogen ara bá ti ń dínkù tí a máa ń rí ti obìrin bá tí ń súmón ojọ́ orí tí wọn kò lè bímọ mọ́.

Orúkọ mons pubis jẹyọ láti èdè Latin fún "pubic mound", àti mons Venus tàbí mons veneris  jẹyọ láti èdè Latin fún "mound of Venus".

Àwọn ìtọ́kasí

Àwọn ìwé ìtàn

Àwọn àjápọ̀ látìta

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

David GrossLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Sàmóà Amẹ́ríkàNarmerKárbọ̀nùAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ FuforeGarba LawalLinda IkejiÌwo Orí ilẹ̀ ÁfríkàBachir GemayelFrank Pieter IsraelẸ̀kùàdọ̀rÀjàkáyé-àrùn èrànkòrónà ọdún 2019-2020BeninÀtòjọ àwọn orílẹ̀-èdè Olómìnira àgbáyéNomba atomuBauchiÈre ÒmìniraIlú-ọba Ọ̀yọ́CalabarOgun láàrin Ùgándà àti TànsáníàISO 639-2ArgẹntínàPeso convertibleIfáAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìwọòrùn UkwaPópù VigiliusÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020Èdè FiẹtnámHTMLÀkójọ àwọn olúìlú orílẹ̀-èdè ní Europe gẹ́gẹ́ bíi ààlàJacob ZumaStuttgartZLana JurčevićDomain Name SystemAyéÀsìá ilẹ̀ AlbáníàVicente FernándezZambiaSteve GukasEfinrinÈṣùMọ́remí ÁjàṣoroHans Georg DehmeltDas Schloß (Ìwé).pmMẹ́ksíkòNational Basketball AssociationCristiano RonaldoBrasilSarzFransiÈdè Urdu108 HecubaPólàndìLakshadweepAsiri ọkunrin club (نادي الرجال السري)YorùbáFijiDomingo CaycedoIrinÈdè PólándìPọ́rtúgàlJessica TandyÈdè Húngárì🡆 More