Àwọn Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn

Àwọn ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn ni awo eto ipile ati ominira ti gbogbo awon omo eniyan leto si.

Nitorie awon eto omoniyan je gbigba bi ti eyi to je alagbalaaye ati bakanna. Iru awon ajemonu bayi le wa gege bi awon asa awon iwuwa eniyan gangan, gege bi asa iwa tito tabi awon eto eda ti o ni idi pataki, tabi gege bi awon eto olofin boya ninu orile-ede tabi ninu ofin kariaye. Sibesibe, ko si ikoenu lori kini ohu pato to je tabi ti ko je eto omoniyan lona kankan, be si ni ero awon eto omoniyan bi afoyemo ti je ohun ijiyan ati igbeyewo ninu imo oye.

Àwọn Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn
Magna Carta je gbigbejade ni Ilegeesi ni 1215.

ero odeoni nipa awon eto omoniyan dide leyin isele Ogun Agbaye Keji, gege bi idahun si Ipaniyanrun àwon Ju, eyi fa itowobowe Ìkéde Akáríayé fún àwọn Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn latowo United Nations General Assembly ni 1948.



Itokasi

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

YorùbáLeadÀdánidáKòkòròỌ̀rúnmìlàEsther OyemaSQL19 SeptemberAtọ́ka Ìdàgbàsókè ÈnìyànOgunNọ́mbà átọ̀mù21 June67085 OppenheimerÀṣà Ìsọmọlórúkọ Nílẹ̀ YorùbáIfe Ẹ̀yẹ Àgbáyé FIFA 2006ỌdúnRalph BuncheSamuel Ajayi CrowtherErékùṣù1 AugustChinedu IkediezeÌwé Àṣẹ Aṣàlàyé Ọ̀fẹ́ GNUÀrún èrànkòrónà ọdún 2019MichiganHọ́ng KọngBrie LarsonÀlọ́Oṣù KẹtaMao ZedongẸyẹTunisiaAustrálíàWale OgunyemiÀgbáyéÒṣèlúÀpàlàPópù Alexander 2kLítíréṣọ̀YttriumAbdullahi Ibrahim (ológun)Vladimir PutinHermann HesseFránsìỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Irin1 OctoberOrílẹ̀-èdèAyo AdesanyaArunachal PradeshAntárktìkìNarendra ModiOṣù Kẹ̀sánEmperor ShōmuMuhammadu BuhariOjúewé Àkọ́kọ́zr5oo8 OctoberỌjọ́ 25 Oṣù KẹrinMarcel ProustOrúkọ ìdíléPópù Jòhánù Páúlù ÈkejìArizonaKàríbẹ́ánìOṣù KọkànláMiles DavisMinskWashington, D.C.TiranaR. Kelly🡆 More