Muhammadu Buhari: Aare orile-ede Naijiria tele

Muhammadu Buhari (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ ketàdínlógún, Oṣù Kejìlá Odún 1942) olóṣèlú tí ó jẹ́ Ààrẹ orílè-èdè Nàíjíríà láàrin ọdún 2015 sí ọdún 2023.

Ó lo ṣáà àkọ́kọ́ rẹ̀ láàrin odún 2015 sí 2019 àti kejì láàrin ọdún 2019 sí 2023. Buhari tí fìgbà kan jẹ́ ogágun Méjọ̀ Gẹ́nẹ́rà àti pé ó j̣e olórí orílẹ̀ èdè Nàíjíríà lati 31st Oṣù kejìlá odún 1983 sí Oṣù kẹjó odún 1985, léyìn tí ó fi kúùpù ológun gbàjọba.

His Excellency

Muhammadu Buhari
Muhammadu Buhari: Aare orile-ede Naijiria tele
Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà 7k & 15k
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
29 Oṣù Kàrún 2015
Vice PresidentYemi Osinbajo
AsíwájúGoodluck Jonathan
Chair of the Supreme Military Council
In office
31 Oṣù Kejìlá 1983 – 27 Oṣù Kẹjọ 1985
Vice PresidentTunde Idiagbon (Chief of Staff)
AsíwájúShehu Shagari (President)
Arọ́pòIbrahim Babangida (Chair of the Armed Forces Ruling Council)
Ijoba Ijoba ti Awọn Ọkọ Ẹrọ
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
11 Kọkànlá Oṣù 2015
AsíwájúDiezani Allison-Madueke
Gómínà ìpínlẹ̀ Bọ̀nú
In office
3 Oṣù Kejì 1976 – 15 Oṣù Kẹta 1976
AsíwájúPosition established
Arọ́pòMustapha Amin
Governor of the Northeastern State
In office
1 Oṣù Kẹjọ 1975 – 3 Oṣù Kejì1976
AsíwájúMusa Usman
Arọ́pòPosition abolished
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí17 Oṣù Kejìlá 1942 (1942-12-17) (ọmọ ọdún 81)
Daura, Northern Region, Nigeria
(now Daura, Katsina State, Nigeria)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressives Congress
(Àwọn) olólùfẹ́
Safinatu Yusuf
(m. 1971; div. 1988)

Aisha Halilu (m. 1989)
Àwọn ọmọ10
Alma materNigerian Military Training College
Mons Officer Cadet School
U.S. Army War College
WebsiteOfficial website
Military service
Nickname(s)Baba go slow
AllegianceNàìjíríà Nàìjíríà
Branch/serviceMuhammadu Buhari: Aare orile-ede Naijiria tele Adigun Nàìjíríà
Years of service1961–1985
RankMajor General
*Yemi Osinbajo served as Acting President from 19 January 2017 – 13 March 2017 and 7 May 2017 – 21 August 2017 while Buhari received medical treatment.

Igbesi aye tete

A bí Muhammadu Buhari sí ìdílé Fulani ní ọjọ 17 Kejìlá 1942, ní Daura, Ìpínlè Katsina, baba rẹ ni Hardo Adamu, ẹni tí ó jẹ́ olori Fulani, orúkọ ìyá rẹ̀ sì ni Zulaihat, ẹni tí ó Hausa. Òun ni ọmọ kẹtalelogun bàbá rẹ̀. Ìyá Buhari ni ó tọ dàgbà, bàbá rẹ̀ fi ayé sílè nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rinrin.

Ìgbésí ayé rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Ológun

Buhari dara pò mó Nigerian Military Training College (NMTC) ní ọdun 1962, ó jẹ́ omo odun kan dínlógún nígbà náà. Ní oṣù kejì ọdún 1964, a yí orúkọ ilé-ìwé ológun náà padà sí Nigerian Defence Academy (NDA).

Ní àárín 1962 sí 1963, Buhari kó nípa ìmò ogun ní Mons Officer Cadet School ní ìlú Aldershot, England. Ní oṣù kínní ọdún 1963, nígbà tí Buhari jẹ́ ọmọ ọdún ogún, a sọ́ di lieutenanti kejì.

Àwọn Ìtókasí

Tags:

Nigeria

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

2 AprilJòhánù 1k ilẹ̀ FránsìZulu Sofola147 ProtogeneiaTsílèIbadan Peoples Party (IPP)(4759) 1978 VG10James CoburnOnome ebiỌbàtáláYukréìnRBarbra StreisandWorld Health OrganizationÀdírẹ́ẹ̀sì IPÒkunCentral African RepublicGlory Alozie.pfSTS-55(213727) 2002 VF92Adeniran OgunsanyaÀgbájọÒjéGordon BrownSantos AcostaTurkmẹ́nìstánValentín Gómez FaríasBan MuangFolashade AbuganÀwọn BàhámàAdijat GbadamosiẸgbẹ́ Dẹmọkrátíkì (USA)Ìṣèlú ilẹ̀ Guinea11 NovemberJean-Paul SartrePaul DiracEhoroSaadatu Hassan LimanTony BlairISO/IEC 8859-3ISO 8601GeorgiaEdmund HusserlBhùtánOnitshaOregonBukola AbogunlokoSeattleHugh CapetÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáÀgùàlàÀwọn TatarLossless JPEGNoam ChomskyWilliam Howard TaftAntarcticaBùrúndìThe New York TimesIfeoma MbanugoBahiaSeun Ajayi🡆 More