Etí jẹ́ ẹ̀yà ara, èyí tí ènìyàn àti ẹranko fi ń gbọ́ ọ̀rọ̀.
Ènìyàn àti ẹran ọ̀sìn, (tí òyìnbó ń pè ní "mammals") ní etí méjì. A lè pín etí sí ẹ̀yà mẹ́ta; etí ìta, etí àárín àti etí inú, awon ẹ̀yà mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yìí ń ṣiṣẹ́ papọ̀ láti mú kí ènìyàn tàbí ẹranko gbọ́rọ̀. Ìjàm̀bá sí etí (pàápàá jù lo; ìlù etí) le fa àìgbọ́ràn tàbí ìṣòro pẹ̀lú ọ̀rọ̀ gbígbọ́.
Etí | |
---|---|
Human (external) ear |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Etí, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.