Aṣọ

Aṣọ jé ohun tí ènìyàń ń wọ̀ láti bo ìhòhò.

Oríṣi ohun èlò ni a fi ń hun aṣọ, àwọn ohun èlò bíi òwú, ọ̀rá, awọ sílìkì àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ, lẹ́yìn híhun aṣọ, aṣọ tún nílò rírán kí ó tó le di wíwọ̀. Yàtò sí fún bíbo ìhòhò, aṣọ tún wà fún oge àti ìdánimọ. Àpẹẹrẹ oríṣi aṣọ ilé Yorùbá ni ìró àti bùbá, Agbádá, dànsíkí, búbù, kẹ̀mbẹ̀, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. (ní òpòlopò ìgbà) olùwọ àwọn asọ wọ̀nyí ma ń jé ọmọ Yorùbá .

Orisirisi aso ní ilè Yorùbá

Ìró àti Bùbá

• Agbádá

• Ìpèlé

Àwon Ìtókasí

Tags:

AgbádáOwuYorùbáÌró ati bùbá

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

.uyUrho KekkonenẸ̀wádún 2010.bwÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Ẹ́gíptìAustrálíàVladimir LeninIrinMikhail YouzhnyMarco PoloMandy PatinkinMediaWiki3471 AmelinGrace EborFúnmiláyọ̀ Ransome-KútìSalif Keita (footballer)Ilẹ̀ YorùbáMamerto UrriolagoitiaÀwọn ará Jẹ́mánìÌwé Àṣẹ Aṣàlàyé Ọ̀fẹ́ GNUMoky MakuraOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́Corine Onyango.рфPópù Celestine 2kKunle AfolayanErékùṣù ÀjíndeÌbálòpọ̀Sigourney WeaverMariah CareyÀsìá ilẹ̀ Bẹ̀rmúdà2024Nelson Mandela29 JuneErnest MonisKárbọ̀nùFàdákàÀjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ní àwọn Erékùṣù KánárìLouis St. LaurentErékùṣù Brítánì OlókìkíWikimediaÌdíje Wimbledon 1979 − Àwọn Obìnrin ẸnìkanÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ BrasilÈdè LárúbáwáÌdíje Wimbledon 1977 − Àwọn Obìnrin ẸnìkanGómìnàAlbert Szent-GyörgyiNgozi NwosuÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáMustapha IsmailÌjọba àìlólóríÌtannáEmperor SeiwaTaiwo Odukoya67085 OppenheimerPonun StelinLimaỌ̀rọ̀ ìṣeÒgún LákáayéHassiomuEsther OnyenezideSt. John's (Ántígúà àti Bàrbúdà)Margaret ThatcherẸ̀bùn Nobel nínú Ìṣiṣẹ́ògùn🡆 More