The Beatles je egbe olorin Geesi rock, O je diddasile ni Liverpool ni 1960 be sini o je ikan ninu awon olorin to yori si rere julo ati ti o gba ayewo daada julo ninu itan orin togbajumo.
Lati 1962 egbe olorin yi ni John Lennon (rhythm guitar, olukorin), Paul McCartney (bass guitar, vocals), George Harrison (lead guitar, vocals) ati Ringo Starr (ilu, vocals).
The Beatles | |
---|---|
The Beatles in 1964 Clockwise (from top left): John Lennon, Paul McCartney, Ringo Starr, George Harrison | |
Background information | |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Liverpool, England |
Irú orin | Rock, pop |
Years active | 1960–1970 |
Labels | EMI, Parlophone, Capitol, Odeon, Apple, Vee-Jay, Polydor, Swan, Tollie, UA |
Associated acts | The Quarrymen |
Website | www.TheBeatles.com |
Members | John Lennon Paul McCartney George Harrison Ringo Starr |
Past members | Stuart Sutcliffe Pete Best |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article The Beatles, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.