Èdè Afaaru

Afaaru

Avar

Ọmọ ẹgbẹ́ àwọn èdè tí wọ́n ń pè ní Dagestanian ni eléyìí. Dangestanian yìí tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ fún àwọn èdè tí wọ́n ń pè ní Caucasian. Àwọn tí ó ń sọ Caucasian yìí tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹgbẹ̀tà ní Caucasus ní pàtàkì ní ìpínlẹ̀ Dagestan ní Rọ́síà àti Azerbaijan. Àkọtọ́ Cyrillic ni wọ́n fi kọ ọ́ sílẹ̀. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀yà ní àdúgbò yìí ni wọ́n ń lò wọ́n gẹ́gẹ́ bí èdè ìṣèjọba. Àwọn Andi àti Dido náà wà lára àwọn ẹ̀yà tí ó ń lò wọ́n.


Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

AntárktìkìAlifabeeti OduduwaItan Ijapa ati AjaElihu RootÈdè iṣẹ́ọbaSalawa AbeniỌjọ́ àwọn ỌmọdéMinnesotaỌya20634 MarichardsonCondoleezza RiceKàríbẹ́ánìMuhammadu Buhari3 NovemberAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ AleiroGeorge Walker BushÈbuJerseyKárbọ̀nùÒrìṣà Agẹmọ.jpMinskDohaAustrálíàZheng HeNiger (country)Ìṣekọ́múnístì22 DecemberISBN10 AprilISO 3166-1Louis 13k ilẹ̀ FránsìÀrún èrànkòrónà ọdún 2019Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ BindawaÈdè Faransé5 AugustRichard WagnerISO 639-1Florence Griffith-JoynerỌdúnÈdè TháíÀmì-ìdámọ̀ kẹ́míkàPópù Alexander 2kInternetDiamond JacksonOrúkọ YorùbáMaria Najjuma26 JuneChemical elementMike EzuruonyeEukaryaLucie ŠafářováRichard Mofe DamijoBhumibol AdulyadejOṣù KejeFẹlá KútìTegucigalpaPornhub29 May8 NovemberWoodrow WilsonWalter Rudolf HessAbubakar Tafawa BalewaIlẹ̀ọba Aṣọ̀kan25 MarchWikipedia🡆 More