Baktéríà

Baktéríà ( (ìrànwọ́·info); ìkan: Bakterio) je idipo ninla awon ohun elemintintinni prokarioti ti won ni ahamo eyokan.

Gigun won je mitatintinni, idasi bakteria je orisirisi, lati roboto de opa de ilo. Bakteria wa nibi gbogbo ni ile-aye, won wu ninu erupe, omi kikan gbigbona, idoti,omi, ati jinjin ninu ile aye, bakanna ninu elo elemin, ati ninu ara awon ogbin ati eranko. 40 legbegberun ahamo bakteria ninu erupe gramu kan be sini egbegberun kan ahamo bakteria lo wa ninu omi; lapapo egbegberunkesan marun (5×1030) bakteria lowa ni aye ti won sedajo opo isupoalaaye ni agbaye.

Baktéríà
Temporal range: Archean or earlier - Recent
Baktéríà
Scanning electron micrograph of Escherichia coli bacilli
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Àjákálẹ̀:
Bacteria
Phyla
  • gram positive/no outer membrane

Actinobacteria (high-G+C)
Firmicutes (low-G+C)
Tenericutes (no wall)

  • gram negative/outer membrane present

Aquificae
Bacteroidetes/Chlorobi
Chlamydiae/Verrucomicrobia
Deinococcus-Thermus
Fusobacteria
Gemmatimonadetes
Nitrospirae
Proteobacteria
Spirochaetes
Synergistetes

  • unknown/ungrouped

Acidobacteria
Chloroflexi
Chrysiogenetes
Cyanobacteria
Deferribacteres
Dictyoglomi
Fibrobacteres
Planctomycetes
Thermodesulfobacteria
Thermotogae



Itokasi

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Yemoja30 MarchWiki CommonsỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Jack LemmonLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Ọ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)BahrainEre idarayaÀdírẹ́ẹ̀sì IPEarthSean ConneryIni Dima-OkojieIsaiah WashingtonKọ̀mpútàLiberia(211536) 2003 RR11AustrálíàWalter MatthauEl SalfadorJẹ́mánìPópù SabinianMẹ́ksíkòOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́Francis Bacon(213893) 2003 TN2Alẹksándrọ̀s OlókìkíEzra OlubiLyndon B. JohnsonPópù Gregory 16kBeirutFáwẹ̀lì YorùbáÀrokòVladimir NabokovJésùWasiu Alabi PasumaPópù Benedict 16kLinda IkejiOjúewé Àkọ́kọ́1117 ReginitaÌjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020Onome ebiPólándìÀkójọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ NàìjíríàAli Abdullah Saleh23 JuneWikiHTMLMicrosoftYBaltimore3GP àti 3G2🡆 More