Òṣùpá

Òṣùpá (aami: ) jẹ́ olùyípo (satellite) ilẹ̀-Ayé.

Arinidaji jíjìnnà sí láti ilẹ̀-ayé títí dé orí òṣùpá jẹ́ kìlómítà 384,403. Ìwọ̀n ìdábùú òbírí yìí fi ìlọ́pò ọgbọ̀n jù ti ilẹ̀-ayé. Ìlà-àárín òṣùpá jẹ́ kìlómítà 3,474 - tó jẹ́ pé díẹ̀ ló fi jù ọ̀kan nínú mẹ́rin lọ sí ti ilẹ̀-ayé. Èyí sì jẹ́ pé kíkún-inú (volume) òṣùpá jẹ́ ìdá àádọ́ta péré ti ilẹ̀-ayé. Fífà ìwúwosí rẹ̀ jẹ́ ìdá mẹ́fà sí ti ilẹ̀-ayé. Òṣùpá ń yípo ilẹ̀-ayé ní ẹ̀ẹ̀kan láàárín ọjọ́ 27.3 (1 oṣù; ọjọ́ mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n ó lé ní wákàtí mẹ́ta).

Òṣùpá
Òṣùpá
Òṣùpá
Òṣùpá ati Ilé-ayé


Itokasi

Tags:

AyéOṣù

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Mọ́remí ÁjàṣoroDomain Name SystemAbubakar MohammedLinuxOrílẹ̀ èdè AmericaOctave MirbeauYunifásítì HarvardWikisourceJulie ChristiePópù SabinianOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́IfáẸyẹMegawati SukarnoputriÀṣà YorùbáJakartaMẹ́ksíkòOlógbòÀwọn Òpó Márùún ÌmàleỌ̀rànmíyànÀrún èrànkòrónà ọdún 2019Olu FalaeOpeyemi AyeolaVladimir NabokovEarthLudwig van BeethovenẸ̀sìnIsiaka Adetunji AdelekeFísíksìAyéÀjẹsára Bacillus Calmette–GuérinKetia Mbelu1151 IthakaGoogleRio de JaneiroJohn GurdonSaheed OsupaMaseruJapanPópù LinusÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáOlóṣèlúÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáÌtànNew JerseyAlẹksándrọ̀s OlókìkíOSI modelSean ConneryOranmiyanIsaiah WashingtonÒrùnOnome ebiBeirut🡆 More