Ẹranko Elégungun

Ẹranko elégungun /ˈvɜːrtəˌbrəts/ ni ó kó gbogbo ẹ̀yà ẹranko tí wọ́n jẹ́ lára ẹbí (subphylum) ẹranko elégungun ma ń sábà ní /ʔə/ chordates (egungun ẹ̀yìn).

Ẹranko elégungun ni wọ́n jẹ́ púpọ̀ níní ẹbí phylumChordata, tí wọ́n tó ẹgbẹ̀rún lé láàdọ́rin àti ọgórùn ún ó dín méje (69,963) níye ẹ̀yà tí a gbọ́ nípa wọn. Lála àwọn àkójọpọ̀ àwọn ẹranko elégungun ni:

  • ẹja aláìnírùngbọ̀n
  • Ní abẹ́ ẹ̀yà ẹranko elégungun onírùngbọ̀, ni a ti lè rí àwọn ẹranko bíi ẹjà cartilaginous (ẹja ṣáàkì, rays, àti ratfish)
  • Ní abẹ́ ẹ̀yà ẹranko elégungun tetrapods,ni a ti lè rí amphibians, afàyàfà, ẹyẹ àti àwọn ẹranko afọ́mọlọ́mú gbogbo.
  • ẹja eléegun púpọ̀
Ẹranko elégungun
Vertebrate
Temporal range:
Cambrian–Present, 520–0 Ma
Ẹranko Elégungun
Example of vertebrates: a Siberian tiger (Tetrapoda), an Australian Lungfish (Osteichthyes), a Tiger shark (Chondrichthyes) and a River lamprey (Agnatha).
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ]
Ìjọba: Animalia (Àwọn ẹranko)
Ará: Chordata
Clade: Olfactores
Subphylum: Vertebrate
J-B. Lamarck, 1801
Simplified grouping (see text)
  • Fishes (cladistically including the Tetrapods)
Synonyms

Ossea Batsch, 1788

Àwọn Ìtọ́ka sí

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Ìjìláyípo Ilẹ̀-OlóoruHawaiiLátfíàPópù Alexander 7kAcehAli NuhuHelmut SchmidtThe BeatlesÀwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkàArgẹntínàCreative Commons67085 OppenheimerÌran YorùbáÀjọ tí ó ń mójú tó ońjẹ àti oògùn ti orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkàHerbert KroemerAwonÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 1984Joseph E. StiglitzEre idaraya14 DecemberW. E. B. Du BoisMediaWikiÒfinEtta JamesGermansJulie AndrewsIslamÀwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kanAntárktìkàPópù Celestine 3kPópù SymmachusItálíàJesse Jackson, Jr.TexasEre-idaraya abeleGreenland SeaRichard WrightẸranko afọmúbọ́mọKerry WashingtonÀwọn Erékùṣù KáímànPópù Jòhánù 4kToyotaMeles ZenawiTheodore RooseveltYerevanUSAJeremy BenthamAnna NetrebkoDohaOrílẹ̀-èdè olómìniraHavanaEast TimorṢàngóHalle BerryÒkun Kàríbẹ́ánìSão PauloMẹ́tálọ́ìdìÈdè SérbíàÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 1924BerneRọ́síàVirginia WadeOrílẹ̀-èdè Olómìnira Sófìẹ̀tì Sósíálístì ti UkraineVáclav HavelÒkun DúdúKhan Abdul Ghaffar KhanÈbuKaliningrad OblastMáàdámidófò🡆 More