Ali Nuhu Mohammed (táabì ni ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù kẹta, ọdún 1974) jẹ́ òṣèré ará Nàìjíríà àti olùdarí.Ó má ń ṣe ère Haúsá àti ère Gẹ̀ẹ́sì.
ẹ̀ka òwò | film industry, Ètò amóhùn máwòrán ti Nàíjíríà |
---|---|
ẹ̀yà | akọ |
country of citizenship | Nàìjíríà |
name in native language | Ali Nuhu Mohammed, Ali nuhu |
orúkọ àbísọ | Ali Nuhu Mohammed |
orúkọ àfúnni | Ali |
ọjó ìbí | 15 Oṣù Kẹta 1974 |
ìlú ìbí | Maiduguri |
native language | Èdè Haúsá, Waja |
languages spoken, written or signed | gẹ̀ẹ́sì, Èdè Haúsá, Èdè Lárúbáwá, Nigerian Pidgin |
iṣẹ́ oòjọ́ rẹ̀ | òṣèré, film director, olóòtú eré, screenwriter |
ẹ̀kà iṣẹ́ | theater arts |
kẹ́ẹ̀kọ́ ní | Yunifásítì ìlú Jos |
academic degree | bachelor's degree, Bachelor of Arts |
residence | Kánò |
work period (start) | 1999 |
religion or worldview | Ìmàle |
eye color | black, brown |
hair color | Irun dúdú |
official website | http://www.alinuhu.net |
personal pronoun | L485 |
Àwọn òní ròyìn má ń pè ní "king of kannywood" tàbí "sarki". Kannywood ni orúkọ ilé ìṣe fímù Hausa. Nuhu ti kópa nínú àwọn ère Nollywood Àti Kannywood tí ó tó Ẹ̀dẹ́gbẹ́ta filmu.
Nuhu jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Maiduguri, Borno State ní Àríwá Ìwọ̀ Òrùn. Bàbá rẹ̀, Nuhu Poloma jẹ́ ọmọ Ìlú Balanga ni ìpínlẹ̀ Gombe àti Ìyá rẹ̀, Fátima Karderam Digema jẹ́ ọmọ ìjọba àgbègbè Bama ni ìpínlè Borno.Ó dàgbà sí Ìpínlẹ̀ Jos àti Kano. Ó lọ sí Fáṣítì Jos, níbi tí ó ti gba Oyè ẹ̀kọ́ ní Arts.Ó ṣe Ẹ̀sìn orílè èdè ni Ìbàdàn, Ìpínlẹ̀ Oyo. Ó padà lọ sí University of Southern California fun Ẹ̀kọ́ nínu ṣíṣe fíìmù àti àwọn ọ̀nà sinimá.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ali Nuhu, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.