Ojukokoro

Ojukokoro: Greed, jẹ́ fíìmù orílè-èdè Nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2016.

Ó jẹ́ fíìmù ajẹmọ́-ìà-ọ̀daràn àti ajẹ́mọ́-àwàdà, èyí tí àwọn òṣèré bí i Wale Ojo, Tope Tedela, Charles Etubiebi, Seun Ajayi, Shawn Faqua, Ali Nuhu, Somkele Iyamah, Emmanuel Ikubese àti Afeez Oyetoro kópa nínú rẹ̀. Orúkọ ẹni tó kọ ọ́, tó sì darí rẹ̀ ni Dare Olaitan, Olufemi D. Ogunsanwo sì ló gbe jáde.

Ojukokoro: Greed
Fáìlì:Ojukokoro poster.jpg
AdaríDare Olaitan
Olùgbékalẹ̀Olufemi D. Ogunsanwo
Dare Olaitan
Àwọn òṣèréWale Ojo
Tope Tedela
Charles Etubiebi
Seun Ajayi
Ali Nuhu
Shawn Faqua
Somkele Iyamah
Emmanuel Ikubese
Ìyàwòrán sinimáBaba Agba
OlóòtúSeun Opabisi
Ilé-iṣẹ́ fíìmùSingularity Media
House Gabriel Studios
BCI Studios
OlùpínFilmOne Distributions
Déètì àgbéjáde
  • 17 Oṣù Kọkànlá 2016 (2016-11-17) (AFRIFF)
  • 17 Oṣù Kẹta 2017 (2017-03-17) (Nigeria)
Àkókò110 minutes
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèEnglish
Yoruba
Bini

Olaitan kọ ìtàn Ojukokoro ní ọdún 2014, èyí sì jẹ́ fíìmù rẹ̀ àkọ́kọ́ tí wọ́n máa gbé jáde. Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹta ọdún 2017 ni wọ́n gbé fíìmù náà jáde.

Àhunpọ̀ ìtàn

"Ojukokoro dá lórí ìtàn alábòójútó ilé epo kan tó pinnu láti ja àwọn òṣìṣẹ́ rè lólè. Nínú ìrìn-àjò yìí ló ti ṣàwárí pé òun nìkan kọ́ ló ní irú èrò yìí lọ́kàn, tí ó sì tún kíyèsi pé tí ènìyàn bá ní ìdí pàtàkì láti ṣe nǹkan, ìyẹn ò ní kó jẹ́ ohun tó dára."

Àwọn akópa

Àgbéjáde

Ìyàwòrán bẹ̀rẹ̀ ní oṣù kẹrin ọdún April 2016. Wọ́n sì ṣàgbéjáde ìpolówó lérèfé ti fíìmù náà ní oṣù kẹwàá ọdún 2016. Ní oṣù kìíní ọdún 2017, wọ́n ṣàgbéjáde ìpolówó fíìmù náà ní kíkun.

Ìgbéjáde fún ìwòran

Wọ́n ṣàgbéjáde fíìmù Ojukokoro ní àwọn sinimá káàkiri ilẹ̀ Nàìjíríà ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹta ọdún 2017.

Wọ́n ṣá̀fihàn Ojukokoro ní Metrograph, ní New York, ní osù kẹrin, láti ọjọ́ kẹtàlá títí wọ ọjọ́ karùndínlógún ọdún 2018.

Ní oṣù kẹrin ọdún 2021, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣàfihàn rẹ̀ lórí Netflix, ní USA.

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

Ojukokoro Àhunpọ̀ ìtànOjukokoro Àwọn akópaOjukokoro ÀgbéjádeOjukokoro Ìgbéjáde fún ìwòranOjukokoro Àwọn ìtọ́kasíOjukokoroAfeez OyetoroAli NuhuNàìjíríàSeun AjayiSomkele IyamahTope TedelaWale Ojo

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Orin Rhythm and bluesMyanmarThe GuardianÀtòjọ àwọn ìlú àti ìlú-ńlá ní ìpínlẹ̀ AlabamaJosip Broz TitoOgunSARS-CoV-2Bernice Carr VukovichSukarnoSaint PetersburgJason AlexanderÌlúDelhi TitunPragueWeird Al YankovicCleopatra VIISaint Obi27 MarchMao ZedongHelmut SchmidtÁntígúà àti BàrbúdàÌjìláyípo Ilẹ̀-OlóoruÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàPharaohMeles ZenawiDọ́là Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàMichael JordanÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ MàkáùJésùIyipada oju-ọjọ ni AmẹrikaYejide KilankoSaint Kitts àti NevisAustrálíà11 April.idTóngàSmenkhkareMayotteArkansasKerry WashingtonPópù Leo 10kBayern MunichÀsìkòDomitianMàkáùIndiana PacersMarlee MatlinOduduwaSão PauloAli NuhuỌ̀rànmíyànJosephine BakerKate WinsletInternetMario BooysenEuropeEre-idaraya abeleÀjọ àwọn Orílẹ̀-èdèÀwọn ÁràbùPópù Fransisi 1kYorùbáWilliam ShakespeareÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáChinaza UchenduAyò ọlọ́pọ́nRáràẸ̀sìn KrístìIstanbulAzerbaijanWokingBoris Johnson🡆 More