Chinaza Love Uchendu (tí wọ́n bí ní 3 December 1997) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó máa ń gbá bọ́ọ̀lù káàkiri àgbáyé, tó máa ń wà nípò agbedeméjì.
Ó jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ Nigeria women's national football team.
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Chinaza Love Uchendu | ||
Ọjọ́ ìbí | 3 Oṣù Kejìlá 1997 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Lagos, Nigeria | ||
Ìga | 1.72 m (5 ft 71⁄2 in) | ||
Playing position | Midfielder | ||
Club information | |||
Current club | Galatasaray | ||
Number | – | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2017–2018 | Rivers Angels | ||
2018–2020 | Braga | ||
2020 | Linköpings FC | 1 | (0) |
2022–2024 | Gyeongju KHNP | 0 | (0) |
2024– | Galatasaray | 0 | (0) |
National team | |||
2018– | Nigeria | ||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Uchendu gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ Rivers Angels ní Nigeria Women Premier League, láti ọdún 2017 wọ oṣụ̀ keje ọdún 2018. Lẹ́yìn náà ni wọ́n gbe lọ sí ìlú Portugal, pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ Braga.
Lásìkò ìdíje Africa Women Cup of Nations ti ọdún 2018, Uchendu gba bọ́ọ̀lù fún eré àṣekágbà nìkan, níbi tí wọ́n ti mú ú wọlé ní ìsẹ́jú mẹ́jọ, kí eré náà tó parí. Ó ju bọ́ọ̀lù kan wọlé, èyí tó sì mú kí ẹgbẹ́ Nigeria women's national football team ó jáwé olúborí.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Chinaza Uchendu, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.