Ayò Ọlọ́pọ́n

Ayò ọlọ́pọ́n jẹ́ eré ìdárayá ìbílẹ̀ tí ó wọ́pọ̀ láàrín Yorùbá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ayò yí fẹ́ fara pẹ́ Oware tí ó tan kálẹ̀ de orílẹ̀-èdè Amerika, láti ibi òwò-ẹrú.

Ayò Ọlọ́pọ́n
Equipment and initial setup of the Ayoayo game


Ó jẹ́ ọ̀kàn lára àwọn eré àbáláyé. Títa ni à ń ta ayò títa èyí ló bí ìpèdè eré là á fi ọmọ ayò ṣe. Eré pẹ̀lẹ́ pẹ̀lẹ́ ni ayò. Èso sẹ́yò ni wọ́n fi ń ṣe ọmọ ayò, ó máa ń dán bọ́rọ́bọ́rọ́. Àwọn gbẹ́nà-gbẹ̀nà ni wọ́n ń gbẹ́ ọpọ́n ayò. tọkùnrin - tobìnrin ló ń ta ayò.  Àwọn àgbàlagbà ni wọ́n ń sábà máa ń ta ayò

Eré Ayò máa ń jẹ́ kí èèyàn ronú jinlẹ̀, ó ń kọ́ni ni sùúrù, àforítì àti ìfaradà. Ó ń pa ìrònú rẹ̀, Ibùdó ìròyìn ni ìdí ayò.

Àwọn Ayò tí ó jọ Ayò ọlọ́pọ́n

Ọ́pọ̀lọpọ̀ ni àwọn ayò tí ó jẹ́ eré ìdárayá ìbílẹ̀ tí ó ní òfin bí ti àwọn ẹ̀yà ilẹ̀ Afíríkà tókù bi Endodoi tí àwọn ẹ̀yà Maasai tí wọ́n jẹ́ ẹ̀yà kan ní orílẹ̀-èdè Kenya àti Tanzania ń ta.


Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

NàìjíríàYorùbá

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Web browserÌsirò StatistikiAbubakar MohammedI23 JuneAhmed Muhammad MaccidoÀgbérò PythagorasBaltimoreChinua AchebeBeninOṣù KẹtaMurtala MuhammadGuinea-BissauEurope1490 LimpopoIyàrá ÌdánáNew YorkNigerian People's PartyOlódùmarèJẹ́mánìÌbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kán22 DecemberChris BrownÀkójọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ NàìjíríàOrílẹ̀ èdè AmericaẸranko afọmúbọ́mọÀjọ àwọn Orílẹ̀-èdèJack LemmonIfáKàlẹ́ndà GregoryIgbeyawo IpaTashkentEast Caribbean dollarOrílẹ̀Èdè JavaMao ZedongÌṣeọ̀rọ̀àwùjọ(211536) 2003 RR11Ilẹ̀ YorùbáBarry WhiteFilipínìMegawati SukarnoputriPierre NkurunzizaPópù Benedict 16kJésùJakartaÒgbóniPópù SabinianAyéJohn GurdonÌránìAlẹksándrọ̀s OlókìkíBoris YeltsinỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Àwọn orin ilẹ̀ YorùbáThomas CechISO 3166-1 alpha-2🡆 More