Etta James (oruko abiso Jamesetta Hawkins, Oṣù Kínní 25, 1938 - Oṣù Kínní 20, 2012) je akorin blues, soul, R&B, rock & roll, gospel ati jazz ara Amerika.
Eni to bere ise orin kiko larin ewadun 1950, o gbajumo pelu orin bi "Dance With Me, Henry", "At Last", "Tell Mama", ati "I'd Rather Go Blind", awon eyi to ko fun ra re. O koju orisirisi isoro, larin eyi ti se lilo ogun oloro, ko to tun gbe awo rin miran jade ni opin ewadun 1980 pelu awo orin "The seven year Itch".
Etta James | |
---|---|
James ninu ọdún 2006 in Lansing, Michigan | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Jamesetta Hawkins |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Miss Peaches, Íyálàyà R&B |
Ọjọ́ìbí | Los Angeles, California, U.S. | Oṣù Kínní 25, 1938
Aláìsí | January 20, 2012 Riverside, California, U.S. | (ọmọ ọdún 73)
Irú orin | Blues, R&B, rock and roll, jazz, soul, gospel |
Occupation(s) | Singer |
Instruments | Vocals, guitar |
Years active | 1954–2012 |
Labels | Modern, Chess/MCA Records, Argo, Crown, Cadet, Island/PolyGram Records, Private Music/RCA, RCA Victor Records, Elektra, Virgin/EMI Records, Verve Forecast/Universal Records |
Associated acts | Harvey Fuqua, Johnny Otis, Sugar Pie DeSanto |
Won gba pe o se japo orin rhythm and blues ati rock and roll, be sini o gba Ebun Grammy ni emefa ati Ebun Orin Blues ni eme 17. Won fun ni eye fifi si Rock and Roll Hall of Fame ni 1993, si Blues Hall of Fame ni 2001, ati si Grammy Hall of Fame ni 1999 ati 2000. Iwe iroyin olosoosu Rolling Stone fun ni ipo 22 ninu atojo awon akorin 100 to se pataki julo lailai ati ipo 62 ninu atojo awon onisona 100 to se pataki julo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Etta James, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.