Mòsámbìkì

Mozambique, fun ibise Olominira ile Mozambique (Pọrtugí: Moçambique tabi República de Moçambique, pípè ), je orile-ede ni apaguusuilaorun Africa to ni bode mo Okun India ni ilaorun, Tanzania ni ariwa, Malawi ati Zambia ni ariwaiwoorunt, Zimbabwe ni iwoorun ati Swaziland ati Guusu Afrika ni guusuiwoorun.

Republic of Mozambique

República de Moçambique
Orin ìyìn: Pátria Amada
(formerly Viva, Viva a FRELIMO)
Location of Mozambique
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Maputo
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaPortuguese
Vernacular languagesSwahili, Makhuwa, Sena
Orúkọ aráàlúMozambican
ÌjọbaRepublic
• President
Filipe Nyusi
• Prime Minister
Carlos Agostinho do Rosário
Independence
• from Portugal
June 25, 1975
Ìtóbi
• Total
801,590 km2 (309,500 sq mi) (35th)
• Omi (%)
2.2
Alábùgbé
• 2009 estimate
22,894,000 (54th)
• 2007 census
21,397,000 (52nd)
• Ìdìmọ́ra
28.7/km2 (74.3/sq mi) (178th)
GDP (PPP)2008 estimate
• Total
$18.740 billion
• Per capita
$903
GDP (nominal)2008 estimate
• Total
$9.897 billion
• Per capita
$477
Gini (1996–97)39.6
medium
HDI (2007) 0.402
Error: Invalid HDI value · 172nd
OwónínáMozambican metical (Mtn) (MZN)
Ibi àkókòUTC+2 (CAT)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+2 (not observed)
Ojúọ̀nà ọkọ́left
Àmì tẹlifóònù258
ISO 3166 codeMZ
Internet TLD.mz
  1. Estimates for this country explicitly take into account the effects of excess mortality due to AIDS; this can result in lower life expectancy, higher infant mortality and death rates, lower population and growth rates, and changes in the distribution of population by age and sex than would otherwise be expected.

Abe Portugal ni Mozambique wa tele. Bèbè gúsù-ìlà-oòrùn Aáfíríkà ni Mozambique wa. Ó tóbi ju Portugal gan-an lọ. Àwọn ìlú tí ó wà ní bèbè Mozambique bíi Laurence Marquis (tí ó jẹ́ olú-ìlú Mozambique) àti Beira ni àwọn ọkọ̀ ojú omi ti ń gúnlẹ̀. Ọkọ̀ ojú irín ni ó so àwọn ìlú wọ̀nyí mọ́ àwọn ilẹ̀ tí ó kan Mozambique gbàngbàn. Àwọn ènìyàn tí ó wà ní Mozambique tó 7,376,000. Púpọ̀ nínú wọn ni ó jẹ́ Bantu. Púpọ̀ nínú wọn ni ó ń ṣiṣẹ́ ní South Africa níbi tí wọ́n ti ń wa ohun àlùmọ́-ọ́nni ilẹ̀ (minerals). Àwọn mìíràn ń ṣe iṣẹ́ àgbẹ̀. Wọ́n ń gbẹ òwú, kaṣú, ìrèké àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Orí ilẹ̀ pẹẹrẹ ni wọ́nm ti ń gbin àwọn wọ̀nyí. Orí òkè ni wọ́n tí ń gbin tíì (tea).

Vasco da Gama ni ó ṣe àwárí Mozambique ní 1498. Àwọn ara Portugal bẹ̀rẹ̀ síí wá sí ibẹ̀ ní nǹkan bí 1500. Mozambique sì bẹ̀rẹ̀ síí ṣe pàtàkì fún òwò ẹrú. Àwọn ilé-iṣẹ́ (companies) ni ó ń darí ilẹ̀ yìí láti 1891 sí 1942. Ọdún 1942 ni ìjọba Portugal bẹ̀rẹ̀ síí darí ilẹ̀ yìí. Ní 1960 àti 1970, Portugal kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ ogun lọ sí Mozambique láti bá àwọn tí ó ń jà fún òmìnira jà.




Itokasi

Tags:

AfricaIndian OceanMalawiSouth AfricaSwazilandTanzaniaZambiaZimbabween:Wikipedia:IPA for PortugueseÈdè Pọrtugí

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Emilio Aguinaldo20 SeptemberLebanonWikimediaFrançois DuvalierOrílẹ̀-èdè Olómìnira Àrin Ilẹ̀ ÁfríkàÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020Ayo AdesanyaMùhọ́mádùÀtòjọ àwọn orílẹ̀-èdè Olómìnira àgbáyéKuwaitAvicennaOwe YorubaÀrùn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn Ebola27 MarchISO 19439ISO 4Olikoye Ransome-KutiOmahaIdi Amin DadaTony BlairÌṣedọ́gbaÀsà ilà kíkọ ní ilé YorùbáÌṣọ̀kan ÁfríkàÌran Yorùbá2293 GuernicaJustin BieberẸranko afọmúbọ́mọTallinnTurkmenistanÀjàkáyé-àrùn èrànkòrónà ọdún 2019-202029 FebruaryÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàUsherWashington, D.C.1588 DescamisadaAtlantaKọ̀nkọ̀Òrìṣà EgúngúnỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Akínwùmí Iṣọ̀láPalestineCapital cityHTMLGloria EstefanMaltaFáráòIléÌtàn ilẹ̀ MòrókòChlothar 1kSQLAláàfin Ìlú Ọ̀yọ́Ìsirò StatistikiÀgbájọ fún Ìdènà àwọn Ohun Ìjagun Ògùn OlóróPópù Alexander 6kSnoop DoggÌbálòpọ̀Họ́ng KọngAkanlo-edeÈdè Gẹ̀ẹ́sìNẹ́dálándìCreative CommonsISO 3166Usain BoltÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáRọ́síàJanusz WojciechowskiRosa LuxemburgCamillo Benso, conte di Cavour🡆 More