Iyọ̀

Iyọ̀ jẹ alumoni afaralokun tó jẹ́ àkópò sodiomu oniklorini tó ṣé pàtàkì fún ìgbádún eranko, ṣùgbọ́n tí ó le léwu nígbà míràn fún òpò àwọn ogbin orile.

Iyọ̀ wà lára àwọn nkan tí wón ń fi sí oúnjẹ kí ó le dùn, èyí mú kí iyọ̀ jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ǹkan tí àwọn ènìyàn ń lò jù láti mú kí oúnjẹ dùn. Idayobo ni ọ̀nà tí a ń lò láti fi onje pamo.

Iyọ̀
Iyọ̀

Iyọ̀ ti ènìyàn ń jẹ le wá láti oríṣiríṣi ọ̀nà: iyọ̀ àìmó (bi iyo okun), iyọ̀ mímọ (iyo onje), ati iyo oniayodini. A lè rí iyọ̀ láti inú omi okun tàbí àwọn òkúta ilẹ̀.

Àwọn ioni inú iyọ̀ bi Klorínì ati sodiomu, se pàtàkì fún ìwàláàyè gbogbo ohun ẹ̀dá alààyè. Iyọ̀ ń kópa nínú àmójútó omi inú ara, bí ó tilè jẹ́ wípé jíjẹ iyọ̀ jù le fa àìlera fún ara, ó le fa Ẹ̀jẹ̀ ríru.


Itokasi

Tags:

Animal

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

1 OctoberOgun Abẹ́lé Amẹ́ríkàÈdè GríkìBenin17 DecemberTẹknọ́lọ́jìOrúkọ YorùbáBẹ̀lárùsWikipediaW. E. B. Du BoisNàmíbíàAntonio GramsciLanre AlfredYunifásítì KòlúmbíàMontevideo8 NovemberÈdè SpéìnNwando AchebeAntimonyỌbẹ̀Jorge Tadeo LozanoDomain Name SystemCasablanca26 DecemberArméníàWiki CommonsPort-au-Prince28 NovemberAbdullahi Yusuf AhmedẸ̀sìn HinduismMaputoÌwé Dẹutẹ́rónómìMartin Luther King, Jr.Ilẹ̀ YorùbáAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéMalaysiaMáltàÀwọn MaldiveOlúìlúDaniel BernoulliLeonid BrezhnevÒjòOtto von BismarckÀwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáIranIoannis Kolettis12 FebruaryÀwọn èdè Balto-SílàfùLimp BizkitPòtásíọ̀mùGbGuadeloupeÀtòjọ àwọn àjọ̀dúnMichael JacksonRihannaLas VegasNordrhein-WestfalenJohn Maynard KeynesJan TinbergenIfe-ẹ̀yẹ Àgbáyé Bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀Pierre MauroyJa, vi elsker dette landetRobert Robinson (scientist)MolybdenumReese WitherspoonTerry CrewsOlóṣèlúNumerian.bjẸ̀sìn BúddàEre idaraya20 August🡆 More